 |
Wash yourself here. |
 |
 |
fo ara ray neebee |
 |
Fọ ara rẹ̀ẹ́ níbí |
 |
 |
We need ___ liters of potable water. |
 |
 |
a feh gaalo no o mee mee moo ___ |
 |
A fẹ́ gálọ̀nù omi mímu ___ |
 |
 |
Where is the latrine? |
 |
 |
ee boo nee sha laanga wa? |
 |
Ibo ni Ṣálángá wà? |
 |
 |
The latrine is to the ___. |
 |
 |
sha laanga wa nee a Pa ___ |
 |
Ṣálángá wà ní apá ___ |
 |
 |
The latrine is to the left. |
 |
 |
sha laanga wa nee a Pa o see |
 |
Ṣálángá wà ní apá òsì |
 |