Antibiotics
ee Bo gee antee ba yo tee see
Egbògi antibàyọ́tìsì
Bandage
o shoo ka ee way Bo
Òṣùká ìwégbò
Blood
a jeh
Ẹjẹ̀
Burn
jo
Jó
Clean
weh
Wẹ̀ẹ́
Dead
koo
Kú
Doctor
doo kee ta
Dókítà
Fever
ee ba
Ibà
Hospital
ee lay ee wo so
Ilé Ìwòsàn
Infection
ka roo
Kárùn
Injured
shay shay
Ṣè ṣe
Malnutrition
ay jeh hU day day
Àìjẹun deede
Medic
o nee shay ee lay ra
Oniṣẹ́ Ílera
Medicine
a Bo gee
Egbògi
Nurse
no see
Nọ́ọ̀sì
Poison
ma jay lay
Májèlé
Sick
ara o da
Ara ò dá
Vitamins
a Bo gee ka ra o lay
Egbògi Káraóle
Wound
a Bo
Egbò
I am a doctor.
doo kee ta nee mee
Dókítà ni mí
I am not a doctor.
mee key ee shay doo kee ta
Mi kì ìṣe dókítà
I am going to help.
ma a shay ee roH lo wo
Mà á ṣe írànlọ́wọ́
Can you walk?
shay o lay rE?
Ṣé o le rín?
Can you sit?
shay o lay jo ko?
Ṣé o le j'òkó?
Can you stand?
shay o lay do roo?
Ṣé o le dúró?
Are you in pain?
shay aara ohn roo eh?
Ṣé ara n'ro ẹ́?
You will get a shot. (injection)
o ma Ba ah bay reh
O ma gba abẹ́rẹ́
I will take you to the hospital.
ma a moo a lo see ee lay ee wo so
Mà á mú ẹ lọ sí ilé ìwòsàn
What is wrong?
kee lo deh?
Kí ló dé?
Are you injured?
shay o shay shay?
Ṣé o ṣè ṣe?
Can you feed yourself?
shay o lay jeh o fU ra reh?
Ṣé o lè jẹun fún 'ra rẹ?
Open your mouth.
shee a no reh
Ṣí enu rẹ
Are you pregnant?
shay o lo yU?
Ṣé o l'oyún?