 |
We must spend the night here. |
 |
 |
do do nee kee a sU see bee |
 |
Dandan ni kí a sùn síbí |
 |
 |
Is there a dining facility here? |
 |
 |
shay ee bee tee wo tee shay on jeh wa nee bee? |
 |
Ṣé ibi tí nwọ́n ti n'ṣe oúnje wà níbí? |
 |
 |
How many kilometers to the nearest town? |
 |
 |
ma yelee mey lo nee see ee lo to soo mo? |
 |
Máìlì mélòó ni sí ìlú to súnmọ́? |
 |
 |
Are there any hotels near here? |
 |
 |
shay ee lay ee dayra ko ko wa nee to see? |
 |
Ṣé ilé ìdẹ̀ra kankan wà nítòsí? |
 |
 |
Are there any restaurants near here? |
 |
 |
shay ee lay on jeh ko ko wa nee to see? |
 |
Ṣé ilé oúnje kankan wà nítòsí? |
 |