 |
Where is my customs declaration? |
 |
 |
ee bo nee ee way ee boora ee bo day mee wa? |
 |
Ibo ni ìwé ìbúra ibodè mi wà? |
 |
 |
I do not have anything to declare. |
 |
 |
mee ko nee on ko on laatee fee ha |
 |
Mi kò ni oun koun láti fi hàn |
 |
 |
These goods are personal. |
 |
 |
awoH ay roo ee nee mee ray |
 |
Àwọn ẹrù ìní mi rèé |
 |
 |
Not for sale. |
 |
 |
ko see fU tee ta |
 |
Kò sí fún títà |
 |
 |
Can you help me fill out the forms? |
 |
 |
shay o lay roH mee lo wo laatee ko ee da ohn see awoH ee way yee? |
 |
Ṣé o lè ràn mí l'ọ́wọ́ láti kọ ìdáhùn sí àwọn ìwé yìí? |
 |