 |
What is your rank / title? |
 |
 |
kee nee o kU / o ye reh? |
 |
Kí ni okùn / oyè rẹ? |
 |
 |
What is your nationality? |
 |
 |
omo o rey lay ee dee wo nee eh? |
 |
Ọmọ orílẹ̀ èdè wo ni ẹ́? |
 |
 |
Do you have any identification papers? |
 |
 |
shay o nee kaa dee ee daanee mo koH koH lo wo? |
 |
Ṣé o ní káàdì ìdánímọ̀ kankan l'ọwọ́? |
 |
 |
Do you have a passport? |
 |
 |
shay o nee ee way ee rey a jo? |
 |
Ṣé o ní ìwé ìrìn àjò? |
 |
 |
What is your job? |
 |
 |
kee nee ee shay reh? |
 |
Kí ni iṣẹ́ rẹ? |
 |