 |
Please wait for an interpreter. |
 |
 |
jo wo doroo fU o loo too moo |
 |
Jọ̀wọ́ dúró fún olùtumọ̀ |
 |
 |
Please turn off your camera. |
 |
 |
jo wo Pa eh ro a ya fo to reh |
 |
Jọ̀wọ́ pa ẹ̀rọ aya fọ́tọ̀ rẹ |
 |
 |
Please turn off your recorder. |
 |
 |
jo wo Pa eh ro a Ba oo hu reh |
 |
Jọ̀wọ́ pa ẹ̀rọ agba ohùn rẹ |
 |
 |
Here is a copy of our ground rules. |
 |
 |
ee yee nee ee da ee weh awoH o fee wa |
 |
Èyí ni ẹ̀dà ìwé àwọn òfin wa |
 |
 |
Sign here if you agree to follow the ground rules. |
 |
 |
jo o wa see ee weh yee tee o ba faara moo awoH o fee wa |
 |
Ju ọwọ́ sí ìwé yì í tí o bà f'aramọ́ áwọn òfin wa |
 |
 |
This is not the public affairs office. |
 |
 |
ee be kee ee shay o fee see ee jo ba fU ay to awoH aaraa ee loo |
 |
Ibí kì í íṣe ọ́fìsì ìjọba fún ẹ̀tọ́ àwọn ará ìlú |
 |
 |
I am not an official spokesperson. |
 |
 |
ee mee ko nee o shee sheh a Beh no so fU woh |
 |
Èmi kọ́ ni òṣìṣẹ́ agbẹnusọ fún nwọn |
 |
 |
He does not wish to give an interview. |
 |
 |
aaraa kU rE ko feh ee wa no leh no wo |
 |
Arákùnrin kò fẹ́ ìwánilẹ́nuwò |
 |
 |
She does not wish to give an interview. |
 |
 |
aaraa bE rE ko feh ee wa nee leh no wo |
 |
Arábìrin kò fẹ́ ìwánilẹ́nuwò |
 |
 |
Do not take photos here. |
 |
 |
maa yaa fo to nee bee |
 |
Má á ya fọ́tọ̀ ní'bí |
 |
 |
You cannot enter this area now. |
 |
 |
o ko lay wo ee bee nee a ko ko yee |
 |
O kò le è wọ ibí ní àkokò yì í |
 |
 |
For security reasons, I cannot address this question. |
 |
 |
mee ko lay so roo nee Pa ee bay ray yee nee to ree oo hu a shee ree fU ee da bo bo |
 |
Mi kò le è sọ̀rọ̀ nípa ìbéère yì í nítorí ohun àṣírí fún ìdábòbò |
 |
 |
I cannot address that question until the investigation is finished. |
 |
 |
mee ko lay so roo nee Pa ee bay ray yee a ya fee tee woH baa tee Paa ree ee wa dee |
 |
Mi kò le è sọ̀rọ̀ nípa ìbéère yì í àyàfi tí nwọ́n bá ti parí ìwáàdí |
 |
 |
We do not discuss personnel or equipment strength with the media. |
 |
 |
a ko lay so roo nee Pa awoH o shee sheh taa bee aBa raa eh ro Pay loo awoH o nee roo yE |
 |
A kò le è sọ̀rọ̀ nípa àwọn òṣìṣẹ́ tàbí agbára ẹ̀rọ pẹ̀lú àwọn oníròyìn |
 |
 |
We do not discuss future operations with the media. |
 |
 |
a ko lay so roo nee Pa awoH oo hu tee a feh shay Pay loo awoH o nee roo yE |
 |
A kò le è sọ̀rọ̀ nípa àwọn ohun tí a fẹ́ ṣe pẹ̀lú àwọn oníròyìn |
 |
 |
We do not discuss nuclear operations with the media. |
 |
 |
a ko lay so roo nee Pa a kee tee yaH noo kee la Pay loo awoH o nee roo yE |
 |
A kò le è sọ̀rọ̀ nípa akitiyan núkílíà pẹ̀lú àwọn oníròyìn |
 |
 |
We do not discuss chemical operations with the media. |
 |
 |
a ko lay so roo nee Pa a kee tee yaH ka mee ka lee Pay loo awoH o nee roo yE |
 |
A kò le è sọ̀rọ̀ nípa akitiyan kẹ́míkáàlì pẹ̀lú àwọn oníròyìn |
 |
 |
We do not discuss biological operations with the media. |
 |
 |
a ko lay so roo nee Pa a kee tee yaH ba yoo lo jee ka lee Pay loo awoH o nee roo yE |
 |
A kò le è sọ̀rọ̀ nípa akitiyan bàyọ́lọ́jíkáàlì pẹ̀lú àwọn oníròyìn |
 |
 |
We do not have information on this subject. |
 |
 |
a ko nee ee see loo ree o roo yee |
 |
A kò ní èsì l'órí ọ̀rọ̀ yì í |
 |
 |
Names cannot be released until victims' relatives are notified. |
 |
 |
a ko lay da roo ko awoH tee woH nee pee nee no ee sheh leh naa aa ya fee tee a ba tee soo fU eh bee woh |
 |
A kò le è dá'rúkọ àwọn tí nwọ̀n n'ìpín nínú ìṣẹ̀lẹ̀ ná à àyàfi tí a bá ti sọ fún ẹbí nwọ̀n |
 |