 |
Wear this badge where it can be seen. |
 |
 |
wo baa jee yee see ee bee tee woH aa tee ree |
 |
Wọ báàjì yí sí ibi tí nwọ́n á tí ri |
 |
 |
Leave your camera with this person. |
 |
 |
fee eh roo a ya fo to reh tee ee nee yaH yee |
 |
Fi ẹ̀rọ aya fọ́tọ̀ rẹ ti ènìyàn yí |
 |
 |
Leave your cell phone with this person. |
 |
 |
fee fo ono o wo reh tee ee nee yaH yee |
 |
Fi fóònù ọwọ́ rẹ ti ènìyàn yí |
 |
 |
I am your escort. |
 |
 |
ee mee nee o loo sho reh |
 |
Émi ni olùṣọ́ rẹ |
 |
 |
He is your escort. |
 |
 |
o on nee o loo sho reh |
 |
Òun ni olùṣọ́ rẹ |
 |
 |
Follow them. |
 |
 |
teh leh woh |
 |
Tẹ̀lé nwọn |
 |
 |
You will ride with me in that vehicle. |
 |
 |
waa teh leh mee nee no o ko yeh |
 |
Wà á tẹ̀lé mi nínú ọkọ̀ yẹn |
 |
 |
You will ride with us in this vehicle. |
 |
 |
waa teh leh wa nee no o ko yeh |
 |
Wà á tẹ̀lé wa nínú ọkọ̀ yì í |
 |
 |
You will ride with him in that vehicle. |
 |
 |
waa teh leh o kU rE yee nee no o ko yeh |
 |
Wà á tẹ̀lé okùnrin yì í nínú ọkọ̀ yẹn |
 |
 |
You will ride with her. |
 |
 |
waa teh leh o bE rE yee nee no o ko reh |
 |
Wà á tẹ̀lé obìnrin yì í nínú ọkọ̀ rẹ̀ |
 |