 |
I do not wish to give an interview. |
 |
 |
mee ko feh ee wa nee leh no wo |
 |
Mi kò fẹ́ ìwánilẹ́nuwò |
 |
 |
He does not wish to give an interview. |
 |
 |
aaraa kU rE ko feh ee wa nee leh no wo |
 |
Arákùnrin kò fẹ́ ìwánilẹ́nuwò |
 |
 |
She does not wish to give an interview. |
 |
 |
aaraa bE rE ko feh ee wa nee leh no wo |
 |
Arábìrin kò fẹ́ ìwánilẹ́nuwò |
 |
 |
I am not qualified to answer that question. |
 |
 |
mee ko to laa tee da hu ee bay ray yeh |
 |
Mi kò tọ́ láti dáhùn ìbéère yẹn |
 |
 |
She is not qualified to answer that question. |
 |
 |
aaraa bE rE yee ko to laa tee da hu ee bay ray yeh |
 |
Arábìrin yì í kò tó láti dáhùn ìbéère yẹn |
 |
 |
He is not qualified to answer that question. |
 |
 |
aaraa kU rE yee ko to laa tee da hu ee bay ray yeh |
 |
Arákùnrin yì í kò tó láti dáhùn ìbéère yẹn |
 |
 |
He does not want to answer that question. |
 |
 |
aaraa kU rE yee ko feh da hu ee bay ray yeh |
 |
Arákùnrin yì í kò fẹ́ dáhùn ìbéère yẹn |
 |
 |
She does not want to answer that question. |
 |
 |
aaraa bE rE yee ko feh da hu ee bay ray yeh |
 |
Arábìrin yì í kò fẹ́ dáhùn ìbéère yẹn |
 |
 |
I will not answer this question. |
 |
 |
mee ko nee da hu ee bay ray yee |
 |
Mi kò ní dáhùn ìbéère yì í |
 |
 |
I have no answer at this time. |
 |
 |
mee ko nee ee da hu nee a ko ko yee |
 |
Mi kò ní ìdáhùn ní àkokò yì í |
 |
 |
I would like to stop this interview. |
 |
 |
mo feh daa ee waa nee leh no wo yee doo roo |
 |
Mo fẹ́ dá ìwánilẹ́nuwò yì í dúró |
 |
 |
She would like to stop this interview. |
 |
 |
aaraa bE rE feh daa ee wa nee leh no wo yee doo roo |
 |
Arábìrin fẹ́ dá ìwánilẹ́nuwò yì í dúró |
 |
 |
He would like to stop this interview. |
 |
 |
aaraa kU rE feh daa ee wa nee leh no wo yee doo roo |
 |
Arákùnrin fẹ́ dá ìwánilẹ́nuwò yì í dúró |
 |
 |
No comment. |
 |
 |
ko see eh see |
 |
Kò sí èsì |
 |
 |
Can you please ask the question in simpler language? |
 |
 |
shay o lay jo wo bay eh ray nee eh day tee ko lay? |
 |
Ṣé o lè jọwọ́ bèèrè ní èdè tí kò le? |
 |