 |
___ will be here soon. |
 |
 |
___ ma day laa ee Peh |
 |
___ ma dé láìpẹ́ |
 |
 |
I will call on you to speak. |
 |
 |
maa Pay eh laa tee so roo |
 |
Mà á pè ẹ́ láti sọ̀rọ̀ |
 |
 |
He will call on you to speak. |
 |
 |
aaraa kU rE aa Pay eh laa tee so roo |
 |
Arákùnrin á pè ẹ́ láti sọ̀rọ̀ |
 |
 |
She will call on you to speak. |
 |
 |
aaraa bE rE aa Pay eh laa tee so roo |
 |
Arábìrin á pè ẹ́ láti sọ̀rọ̀ |
 |
 |
Please ask only one question each time you are called on. |
 |
 |
jo wo ee bay ray ko nee kee o bay ray nee ee Baa tee a ba Pay eh |
 |
Jọwọ́ ìbéère kan ni kí o bèèrè ní ìgbà tí a bá pè ẹ́ |
 |
 |
You may ask one legitimate follow-up question per turn. |
 |
 |
o see lay bay ray ee bay ray ee teh lay gee dee ko see nee ee Ba tee eh |
 |
O sì lè béèrè ìbéère ìtẹ̀lé gidi kan si ní ìgbà tì ẹ |
 |
 |
Please wait for the interpreter to translate your question. |
 |
 |
jo wo doo roo fU o loo to mo laa tee waa to mo ee bay ray reh |
 |
Jọwọ́ dúró fún olùtumọ̀ láti wá túmọ̀ ìbéère rẹ |
 |
 |
Please wait for the interpreter to translate your answer. |
 |
 |
jo wo doo roo fU o loo to mo laa tee waa to mo ee da hu reh |
 |
Jọwọ́ dúró fún olùtumọ̀ láti wá túmọ̀ idáhùn rẹ |
 |
 |
That is a separate question; there may be time to address it later. |
 |
 |
eh bay ray o to nee yeh; a yee lay waa fU nee a ko ko meeraH |
 |
Ìbéère ọ̀tọ̀ nìyẹn; àyè lè wá fún ní àkokò míràn |
 |
 |
We ran out of time. |
 |
 |
a ko ko tee lo |
 |
Àkokò ti lọ |
 |
 |
If he promised you information, be sure to give your contact information to ____. |
 |
 |
tee aaraa kU rE baa Peeno laa tee so roo fU eh, ree wee Peh o fee ee laa no bee woH aa shay ko see eh see leh fU ___ |
 |
Tí arákùnrin bá pinu láti s'ọ́rọ́ fún ẹ, rí wípé o fi ìlànà bí nwọ́n á ṣe kàn sí ẹ sílẹ̀ fún ___ |
 |
 |
If she promised you information, be sure to give your contact information to her. |
 |
 |
tee aaraa bE rE baa Peeno laa tee so roo fU eh, ree we Peh o fee ee laa no bee aa shay ko see eh see leh fU |
 |
Tí arábìnrin bá pinu láti s'ọ́rọ́ fún ẹ, rí wípé o fi ìlànà bí á ṣe kàn sí ẹ sílẹ̀ fún |
 |
 |
If I promised you information, be sure to give your contact information to me. |
 |
 |
tee mo baa Peeno laa tee so roo fU eh, ree wee Peh o fee ee laa no bee mo shay ma ko see eh fU mee |
 |
Tí mo bá pinu láti s'ọ́rọ́ fún ẹ, rí wípé o fi ìlànà bí mo ṣe ma kàn sí ẹ fún mi |
 |
 |
Another session will take place later today. |
 |
 |
ee Pa day mee roo yo wa nee eh nee |
 |
Ìpàdè míràn yíò wà ní èní |
 |
 |
Thanks for your cooperation. |
 |
 |
o shay fU ee fo wa so wa Poo reh |
 |
O ṣé fún ìfọwọ́sowọ́pọ̀ rẹ |
 |