 |
I am not an official spokesperson. |
 |
 |
ee mee ko nee o shee sheh a Be no so fU woH |
 |
Èmi kọ́ ni òṣìṣẹ́ agbẹnusọ fún nwọn |
 |
 |
Please wait for the public affairs representative. |
 |
 |
jo wo doo roo fU a Be no so fU eh to awoH aaraa ee loo |
 |
Jọwọ́ dúró fún agbẹnusọ fún ẹ̀tọ́ àwọn ará ìlú |
 |
 |
I can only tell you what I know. |
 |
 |
in ko tee mo baa mo nee mo lay soo fU eh |
 |
Nkan tí mo bá mọ́ ni mo lè sọ fún ẹ |
 |
 |
The situation is under control. |
 |
 |
ee sheh leh no tee lay to |
 |
Ìṣẹ̀lẹ̀ náà ti l'ètò |
 |
 |
We are doing everything we can to restore order. |
 |
 |
aa on shay BoBo oo hu tee a lay shay laa tee jeh kee o lay to |
 |
À nṣe gbogbo ohun tí a l'èṣe láti jẹ́ kí ó l'ètò |
 |
 |
We are doing everything we can to protect lives. |
 |
 |
aa on shay BoBo oo hu tee a lay shay laa tee da bo bo awoH eh mee |
 |
À nṣe gbogbo ohun tí a l'èṣe láti d'ábòbò awọn ẹ̀mí |
 |
 |
We are doing everything we can to save lives. |
 |
 |
aa in shay BoBo oo hu tee a lay shay laa tee to jo awoH eh mee |
 |
À nṣe gbogbo ohun tí a l'èṣe láti tọ́jú awọn ẹ̀mí |
 |
 |
There was an incident. |
 |
 |
ee sheh leh ko sheh |
 |
Ìṣẹ̀lẹ̀ kan ṣẹ̀ |
 |
 |
The incident is under investigation. |
 |
 |
ee wa dee ee sheh leh no on loo lo wo |
 |
ìwáàdí ìṣẹ̀lẹ̀ ná à nlọ l'ọ́wọ́ |
 |
 |
We are taking this matter very seriously. |
 |
 |
o roo yee shay ko ko fU wa |
 |
Ọrọ̀ yì í ṣe kókó fún wa |
 |
 |
People have been killed. |
 |
 |
awoH ee nee yaH tee koo |
 |
Àwọn ènìyàn ti kú |
 |
 |
Civilians have been killed. |
 |
 |
awoH aaraa ee loo tee koo |
 |
Àwọn ará ìlú ti kú |
 |
 |
Names cannot be released until victims' relatives are notified. |
 |
 |
a ko lay daa roo ko awoH tee woH nee peh nee no ee sheh leh no a ya fee tee a baa tee so fU eh bee woh |
 |
A kò lè dá'rúkọ àwọn tí nwọ̀n n'ìpín nínú ìṣẹ̀lẹ̀ ná à àyàfi tí a bá ti sọ fún ẹbí nwọ̀n |
 |
 |
The official spokesman is expected here soon. |
 |
 |
o shee sheh a Be no so fU woH yo day bee laa ee Peh |
 |
Òṣìṣẹ́ agbẹnusọ fún nwọn yí ò dé 'bí láìpẹ́ |
 |
 |
Appropriate action will be taken. |
 |
 |
woH aa shay oo hu tee o to |
 |
Nwọ́n á ṣe ohun tí ó tọ́ |
 |
 |
We take every report of wrongdoing very seriously. |
 |
 |
oo hu eh so ee wah kee wa jeh ko ko fU wa |
 |
Ohun ẹ̀sùn ìwàkiwà jẹ́ kókó fún wa |
 |
 |
We have secured the area where the incident occurred. |
 |
 |
a tee da bo bo aBeBe tee ee sheh leh no Bay sheh leh |
 |
A ti d'ábòbò agbègbè tí ìṣẹ̀lẹ̀ náà gbé ṣẹlẹ̀ |
 |
 |
I am sorry but you have to wait for the report. |
 |
 |
maa bee no, o nee laa tee do roo kee ee see jaa day |
 |
Má à bínú, o ní láti dúró kí èsì jáde |
 |