Get Instructions
main picture
Title Bar
Go To Main Menu Print Page previous page PagePage Total next page
Play Button Where and when did you observe the improvised explosive device (IED)? Play Button ee Ba wo a tee ee bo nee o tee ree bomb Pa ja wee ree naa? Ìgbàwo àti ibo ni o ti rí bọ́mùbù pàjáwìrì(IED)ná à?
Play Button Who emplaced the improvised explosive device (IED)? Play Button taa nee o keh bomb Pa ja wee ree naa see leh? Tani ó kẹ́ bọ́mùbù pàjáwìrì(IED)ná à sílè?
Play Button How is the improvised explosive device (IED) detonated? Play Button baa wo nee woH shay in yE bomb boo Pa ja wee ree naa? Báwo ni nwọ́n ṣe n yin bọ́mùbù pàjáwìrì (IED)ná à?
Play Button What types of ammunition are used in the explosive device? Play Button awoH ee roo o ta wo nee woH in lo fU bomb boo Pa ja wee ree naa? Àwọn irú ọta wo ni nwọ́n nlo fún bọ́mùbù pàjáwìrì (IED)ná à?
Play Button Is this improvised explosive device (IED) located in a vehicle? Play Button shay bomb boo Pa ja wee ree wa nee no o ko kaH? Ṣé bọ́mùbù pàjáwìrì (IED)wà nínú ọkọ̀ kan?
Play Button Where is the owner of this vehicle? Play Button ee bo nee a nee tee o nee o ko naa wa? Ibo ni ẹni tí ó ni ọkọ̀ ná à wà?
Play Button Who made the improvised explosive device (IED)? Play Button taa nee o shay bomb boo Pa ja wee ree naa? Tani ó ṣe bọ́mùbù pàjáwìrì (IED)ná à?
Play Button Where was the improvised explosive device (IED) built? Play Button ee bo nee woH tee shay bomb boo Pa ja wee ree naa? Ibo ni nwọ́n ti ṣe bọ́mùbù pàjáwìrì (IED)ná à?
Play Button Where was the improvised explosive device (IED) stored prior to emplacement? Play Button ee bo nee woH to jo bomb boo Pa ja wee ree naa see kee woH to keh see leh? Ibo ni nwọ́n tọ́jú bọ́mùbù pàjáwìrì (IED)ná à sí kí nwọ́n tó kẹ sílẹ̀?
Play Button Is there a second or backup detonator? Play Button shay a nee kay jee wa laa tee yE? Ṣé ẹnìkejì wà láti yì í n?
Play Button Is there a secondary device to attack aid and rescue workers? Play Button shay in ka ee woo ee kay jee wa laatee shay ee jaam ba fU awoH aBa nee lah? Ṣé nkan ewu èkejì wà láti ṣe ìjàmbá fún àwọn agbanilà?
Play Button Who is the target of this improvised explosive device (IED)? Play Button taa nee woH feh shay ee jaam ba fU Pey loo bomb boo Pa ja wee ree yee? Tani nwọ́n fẹ́ ṣe ìjàmbá fún pẹ̀lú bọ́mùbù pàjáwìrì (IED)yì í?
Play Button What else can you tell me about the improvised explosive device (IED) or the individuals involved? Play Button in ka wo nee o to lay so fU mee nee Pa bomb boo Pa ja wee ree yee taa bee awoH tee o wa nee dee reh? Nkan wo ni o tú lè sọ fún mi nípa bọ́mùbù pàjáwìrì (IED)yì í tàbí àwọn tí ó wà ní 'dí rẹ̀?
Go To Main Menu Print Page DLIFLC 2007 previous page PagePage Total next page