 |
Do you have fuel pits? |
 |
 |
shay o nee ee bee tee woH da eh Po see? |
 |
Ṣé o ní ibi tí nwọ́n da epo sí? |
 |
 |
Are firefighters available during refueling? |
 |
 |
shay awoH Pa no Pa no waa tee a baa ohn roo Po? |
 |
Ṣé àwọn panọ́panọ́ wà tí a bá n rọ'po? |
 |
 |
How much fuel do your trucks hold? |
 |
 |
baa wo nee o ko ohn la yE shay ohn jeh eh Po see? |
 |
Báwo ni ọkọ̀ nla yín ṣe n jẹ epo sí? |
 |
 |
We need refueling. |
 |
 |
a feh roo Po |
 |
A fẹ́ rọ'po |
 |
 |
Where will we be refueling? |
 |
 |
ee bo nee a tee ma roo Po? |
 |
Ibo ni a ti ma rọ'po? |
 |