 |
Did you say ___? |
 |
 |
shay oo so Pay ___? |
 |
Ṣé o sọ pé ___? |
 |
 |
I do not speak Yoruban. |
 |
 |
mee ko lay so yo roo ba |
 |
Mi kò lè sọ Yoruba |
 |
 |
Does anyone there speak English? |
 |
 |
shay eh nee tee o lay so o yE bo waa nee beh? |
 |
Ṣé eni tí ó lè sọ òyìnbó wà ní'bẹ̀? |
 |
 |
Am I talking with ___ control? |
 |
 |
shay o loo daa ree ___ nee mo ohn baa so roo? |
 |
Ṣé olùdarí ___ ni mò n bá sọ̀rọ̀? |
 |
 |
Is there a better frequency to communicate? |
 |
 |
shay ee ko nee tee o daa raa jo ee yee lo wa laa tee so roo? |
 |
Ṣé ìkànnì tí ó dára ju èyí lọ wà láti sọ̀rọ̀? |
 |