 |
Is your navigation system working? |
 |
 |
shay eh roo reh tee o ohn jo way o no ohn shee sheh? |
 |
Ṣé ẹ̀rọ rẹ tí ò n júùwé ọ̀nà nṣiṣẹ́? |
 |
 |
I see the airfield. |
 |
 |
mo ree PaPa oo ko baa loo |
 |
Mo rí pápá ọkọ̀ bàálù |
 |
 |
I see the runway. |
 |
 |
mo ree tee tee ee baa leh oo ko baa loo |
 |
Mo rí títì ìbalẹ̀ ọkọ̀ bàálù |
 |
 |
I've landed. |
 |
 |
mo tee baa leh |
 |
Mo ti baalẹ̀ |
 |
 |
Is your Instrument Landing System (VOR, TACAN) working? |
 |
 |
shay eh roo fU awoH eh to ee baa leh ohn shee sheh? |
 |
Ṣé ẹ̀rọ rẹ fún àwọn ètò ìbalẹ̀ nṣiṣẹ́? |
 |