 |
Follow the "follow-me" truck. |
 |
 |
tel lay oo ko ohn laa tee ee jeh "tel lay mee" |
 |
Tẹ̀lẹ́ ọkọ̀ n'lá tí í jẹ́ "Tẹ̀lẹ́ mi" |
 |
 |
Take runway ___. |
 |
 |
Ba tee tee ee baa leh o ko baa loo ___ |
 |
Gba títì ìbalẹ̀ ọkọ̀ bàálù ___ |
 |
 |
Hold short of runway. |
 |
 |
doroo kee oo to day tee tee ee baa leh oo ko baa loo |
 |
Dúró kí o tó dé títì ìbalẹ̀ ọkọ̀ bàálù |
 |
 |
Is able, enter next taxiway. |
 |
 |
o tee yaa, wo tee tee tee oo ko baa loo tin roo seh |
 |
Ó ti yá, wọ títì tí ọkọ̀ bàálù ti n'rosẹ̀ |
 |
 |
Taxi to parking. |
 |
 |
roo seh tee tee oo ma fee wa oo ko saa yeh |
 |
Ro'sẹ̀ títi o ma fi wa ọkọ̀ s'àyè |
 |