 |
We need workers to assist with unloading. |
 |
 |
a feh awoH o shee sheh tee o maa baa wa jaa eh roo |
 |
A fẹ́ àwọn òṣìṣẹ́ tí ó má a bá wa já ẹrù |
 |
 |
We need cargo handlers. |
 |
 |
a feh awoH o shee sheh tee o maa baa wa shay o roo eh roo |
 |
A fẹ́ àwọn òṣìṣẹ́ tí ó má a bá wa ṣe ọ̀rọ̀ ẹrù |
 |
 |
Is there a staging area for cargo? |
 |
 |
shay ee bee eh to awoH eh roo waa? |
 |
Ṣé ibi ètò àwọn ẹrù wà? |
 |