 |
Please unlock the back door. |
 |
 |
jo wo see ee leh kU eh hee |
 |
Jọ̀wọ́ ṣí ìlẹ̀kùn ẹ̀hìn |
 |
 |
We need to inspect the cargo. |
 |
 |
anee laa tee shay aa Beh wo awoH eh roo |
 |
A ní láti ṣe àbẹ̀wò àwọn ẹrù |
 |
 |
What is this? |
 |
 |
kee lay lay yee? |
 |
Kí le léyì í? |
 |
 |
Where did you get this ammunition? |
 |
 |
ee boH loo tee ree awoH oo ta yee? |
 |
Ibo lo ti rí àwọn ọta yì í? |
 |
 |
Who does this ammunition belong to? |
 |
 |
taa nee o nee awoH oo ta yee? |
 |
Tani ó ni àwọn ọta yì í? |
 |