 |
The name of the village |
 |
 |
oo roo ko a boo lay na |
 |
Orúkọ abúlé ná à |
 |
 |
The location of the village |
 |
 |
ee bee tee aa boo lay na waa |
 |
Ibi tí abúlé ná à wà |
 |
 |
Is there road access for cars? |
 |
 |
shay oo na waa fU awoH oo ko aa yoo kaa leh? |
 |
Ṣé ọ̀nà wà fún àwọn ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́? |
 |
 |
Is there a road access for four-wheel drive? |
 |
 |
shay oo na waa fU awoH oo ko o nee taa yaa ohn laa mey rE? |
 |
Ṣé ọ̀nà wà fún àwọn ọkọ̀ oní táyà nlá mẹ́rin? |
 |
 |
Is there a road access for trucks? |
 |
 |
shay oo na waa fU awoH oo ko ohn laa? |
 |
Ṣé ọ̀nà wà fún àwọn ọkọ̀ nlá? |
 |
 |
Is the road accessible in the winter? |
 |
 |
shay oo na waa nee Ba oo too too oo yee boH? |
 |
Ṣé ọ̀nà wà n'ígbà òtútù òyìnbó? |
 |
 |
What is the number of the current population? |
 |
 |
awoH may loo nee ohn Beh nee bee nee a koko yee? |
 |
Àwọn mélo ni ó ngbé níbí ní àkokò yì í? |
 |
 |
How many children are there? |
 |
 |
awoH o mo day may loo nee oo waa nee beh? |
 |
Àwọn ọmọdé mélo ni ó wà níbẹ̀? |
 |
 |
How many men are there? |
 |
 |
awoH oo kU rE may loo nee oo waa nee beh? |
 |
Àwọn okùnrin mélo ni ó wà níbẹ̀? |
 |
 |
How many women are there? |
 |
 |
awoH oo be rE may loo nee oo waa nee beh? |
 |
Àwọn obìnrin mélo ni ó wà níbẹ̀? |
 |
 |
How many locals are there? |
 |
 |
awoH aa raa ee loo may loo nee oo wa nee beh? |
 |
Àwọn ará ìlú mélo ni ó wà níbẹ̀? |
 |
 |
How many refugees are there? |
 |
 |
awoH tee oo gU see koo roo may loo nee oo waa nee beh? |
 |
Àwọn tí ogun ṣí kúrò mélo ni ó wà níbẹ̀? |
 |
 |
How many returnees are there? |
 |
 |
awoH tee o seh seh Pa daa day may loo nee oo waa nee beh? |
 |
Àwọn tí ó ṣẹ̀ṣẹ̀ padà dé mélo ni ó wà níbẹ̀? |
 |
 |
Who is the community leader? |
 |
 |
taa nee oo loo ree aBeBe yee? |
 |
Tani olórí agbègbè yì í? |
 |
 |
Who is responsible for food distribution? |
 |
 |
taa nee a so jo fU on jeh Pi Pi? |
 |
Tani asojú fún oúnjẹ pínpín? |
 |
 |
Where is the local warehouse? |
 |
 |
ee boH nee yaa raan laa fU ee Pa mo awoH eh roo tee aBeBe yee waa? |
 |
Ibo ni yàrá nlá fún ìpamọ́ àwọn ẹru ti agbègbè yí wà? |
 |
 |
Is there a storage facility? |
 |
 |
shay yaa raa waa fU ee Pa mo awoH ohn eh loo? |
 |
Ṣé yàrá wà fún ìpamọ́ àwọn ohun èlò? |
 |
 |
Is this village used for secondary distribution? |
 |
 |
shay woH toon ohn loo a boo lay yee fU ohn ko Pi Pi? |
 |
Ṣé nwọ́n tún n lo abúlé yì í fún nkan pínpín? |
 |
 |
Which villages receive assistance from this village? |
 |
 |
awoH a boo lay wo nee woH ohn Ba ee roH loo wo laa tee a boo lay yee? |
 |
Àwon abúlé wo ni nwọ́n n gba ìrànlọ́wọ́ láti abúlé yì í? |
 |
 |
How many damaged houses in this village? |
 |
 |
ee lay may loo nee oo baa jeh nee a boo lay yee? |
 |
Ilé méèlo ni ó bàjẹ́ ni abúlé yì í? |
 |
 |
How many unfinished houses in this village? |
 |
 |
ee lay may loo nee woH ko yee tee Paa ree nee a boo lay yee? |
 |
Ilé méèlo ni nwọ́n kò ì tí ì parí ni abúlé yì í? |
 |
 |
Was there any new war damage to buildings since before the conflict? |
 |
 |
shay awoH ee lay toon tee wo leh hee tee oo gU tee beh reh? |
 |
Ṣé àwon ilé tún ti wó lẹ́hìn tí ogun ti bẹ̀rẹ̀? |
 |
 |
Is there a school in the village? |
 |
 |
shay ee lay ee way waa nee a boo lay na? |
 |
Ṣé ilé ìwé wà ni abúlé ná à? |
 |
 |
Is there a mosque / church in the village? |
 |
 |
shay ee lay ee jo see / mo saa laa see waa nee a boo lay na? |
 |
Ṣé ilé ìjọ́sìn / mọ́ṣáláṣí wà ni abúlé ná à? |
 |
 |
Is there a bakery? |
 |
 |
shay ee lay eh shay boo rey dee waa? |
 |
Ṣé ilé iṣẹ́ búrẹ́dì wà? |
 |