 |
Where can we purchase meat? |
 |
 |
ee boH laa tee lay raa eh roH? |
 |
Ibo lati lè ra ẹran? |
 |
 |
Where can we purchase vegetables and fruit? |
 |
 |
ee boH laa tee lay raa awoH ey way beh aa tee eh so? |
 |
Ibo lati lè ra àwọn ewébẹ̀ àti èso? |
 |
 |
Where can we purchase bread and grains? |
 |
 |
ee boH laa tee lay raa boo rey dee aa tee eh loo? |
 |
Ibo lati lè ra búrẹ́dì àti ẹ̀lọ̀? |
 |
 |
Where can we purchase dairy products? |
 |
 |
ee boH laa tee lay raa awoH waa raa? |
 |
Ibo lati lè ra àwọn wàrà? |
 |
 |
Where can we purchase water? |
 |
 |
ee boH laa tee lay raa o mee? |
 |
Ibo lati lè ra omi? |
 |
 |
We need to examine the herd. |
 |
 |
aa nee laa tee beh awoH eh roH dee daa wo |
 |
A ní láti bẹ àwọn ẹran dídà wò |
 |
 |
We need to examine the animals on the farm. |
 |
 |
aa nee laa tee beh awoH eh roH tee oo wa loko wo |
 |
A ní láti bẹ àwọn ẹran tí ó wà l'óko wò |
 |
 |
We need to inspect the slaughterhouse for sanitation. |
 |
 |
aa nee laa tee beh ee bee tee woH tee ohn Pa awoH eh roH wo fU ee mo to to |
 |
A ní láti bẹ ibi tí nwọ́n ti n pa àwọn ẹran wò fún ìmọ́tótó |
 |
 |
We need to inspect the bakery for sanitation. |
 |
 |
aa nee laa tee beh ee lay ee sheh boo rey dee wo fU ee mo to to |
 |
A ní láti bẹ ilé iṣẹ́ búrẹ́dì wò fún ìmọ́tótó |
 |
 |
We need to inspect the dairy plant. |
 |
 |
aa nee laa tee beh ee lay ee sheh wa raa wo fU ee mo to to |
 |
A ní láti bẹ ilé iṣẹ́ wàrà wò fún ìmọ́tótó |
 |
 |
We need to inspect the poultry plant. |
 |
 |
aa nee laa tee beh ee lay ee sheh awoH aa dee yeh wo fU ee mo to to |
 |
A ní láti bẹ ilé iṣẹ́ àwọn adìyẹ wò fún ìmọ́tótó |
 |
 |
When was the last time these animals were inoculated? |
 |
 |
ee Baa wo nee awoH eh roH yee Ba a beh reh a jeh saa raa Beh yee? |
 |
Ìgbà wo ni àwọn ẹran yì í gba abẹ́rẹ́ àjẹsára gbẹ̀hìn? |
 |
 |
Do they need to be vaccinated? |
 |
 |
shay o yee kee woH Ba a beh reh a jeh saa raa? |
 |
Ṣe ó yẹ kí nwọ́n gba abẹ́rẹ́ àjẹsára? |
 |
 |
We can provide vaccinations. |
 |
 |
a lay fU woH nee a beh reh a jeh saa raa |
 |
A lè fún nwọ́n ní abẹ́rẹ́ àjẹsára |
 |
 |
This food is spoiled; please do not eat it. |
 |
 |
on jeh yee tee baa jeh, jo wo maa shay jeh |
 |
Óunjẹ yì í ti bàjẹ́; jọ̀wọ́ má ṣe jẹ́ |
 |