 |
Do you have an identity card? |
 |
 |
shay o nee ee way ee daa nee mo? |
 |
Ṣé o ní ìwé ìdánimọ̀? |
 |
 |
Show me your identification. |
 |
 |
fee ee way ee daa nee mo reh haH mee |
 |
Fi ìwé ìdánimọ̀ rẹ hàn mí |
 |
 |
How many people live in this area? |
 |
 |
eh nee may loo nee ohn Beh nee aBeBe yee? |
 |
Eni mélo ni ó ngbé ní agbègbè yì í? |
 |
 |
Who is the leader of this community? |
 |
 |
taa nee o loo ree aBeBe yee? |
 |
Tani olórí agbègbè yì í? |
 |
 |
What is his name? |
 |
 |
kee nee o roo ko reh? |
 |
Kíni orúko rẹ̀? |
 |
 |
Please write down his name. |
 |
 |
jo wo ko o roo ko reh see leh |
 |
Jọ̀wọ́ kọ orúko rẹ̀ sílẹ̀ |
 |
 |
Show us the leader. |
 |
 |
fee o loo ree haH waa |
 |
Fi olórí hàn wá |
 |
 |
How many men and women live in this community? |
 |
 |
awoH oo kU rE aa tee o bee rE may loo nee ohn Beh nee aBeBe yee? |
 |
Àwọn okùnrin àti obìnrin mélo ni ó ngbé ní agbègbè yì í? |
 |
 |
How many children live here? |
 |
 |
awoH o mo day may loo nee ohn Beh nee bee yee? |
 |
Àwọn ọmọdé mélo ni ó ngbé níbí yì í? |
 |
 |
Are there schools here for the children? |
 |
 |
shay ee lay ee way fU awoH o mo day waa nee bee? |
 |
Ṣé ilé-ìwé fún àwọn ọmọdé wà níbí? |
 |
 |
Is there enough potable water for the people? |
 |
 |
shay o mee mee moo Po to fU awoH eh nee yaH? |
 |
Ṣé omi mímu pọ̀ tó fún àwọn ènìyàn? |
 |
 |
Is there a water well? |
 |
 |
shay o mee kan ga waa? |
 |
Ṣé omi kànga wà? |
 |
 |
Is there a public fountain? |
 |
 |
shay o mee eh roo mee moo wa fU awoH eh nee yaH? |
 |
Ṣé omi ẹ̀rọ mímu wà fún àwọn ènìyàn? |
 |
 |
Are there any medics here? |
 |
 |
shay awoH o nee wo saH waa? |
 |
Ṣé àwọn oníwòsàn wà? |
 |
 |
Are there any engineers? |
 |
 |
shay awoH en jee nee waa? |
 |
Ṣé àwọn enjiníà wà? |
 |
 |
Are there any teachers? |
 |
 |
shay awoH oo loo ko waa? |
 |
Ṣé àwọn olùkọ́ wà? |
 |
 |
Are there empty buildings here? |
 |
 |
shay awoH ee lay aa hoo roo waa? |
 |
Ṣé àwọn ilé ahoro wà? |
 |
 |
Is there a local police force? |
 |
 |
shay awoH o loo Pa waa? |
 |
Ṣé àwọn ọlọ́ọ̀pá wà? |
 |
 |
Who is responsible for public safety here? |
 |
 |
taa nee ee sheh reh jeh ee daa bo bo awoH eh nee yaH? |
 |
Tani iṣẹ́ rẹ̀ jẹ́ ìdábòbò àwọn ènìyàn? |
 |
 |
Whose responsibility is fire protection? |
 |
 |
taa nee ee sheh reh jeh ee daa bo bo ee na? |
 |
Tani iṣẹ́ rẹ̀ jẹ́ ìdábòbò iná? |
 |
 |
Do you have fire fighting equipment? |
 |
 |
shay eh nee ee rE seh Pa na Pa na? |
 |
Ṣé ẹ ní irinṣẹ́ panápaná? |
 |
 |
Do you have a fire engine? |
 |
 |
shay eh nee oo ko Pa na Pa na? |
 |
Ṣé ẹ ní ọkọ̀ panápaná? |
 |
 |
Who do you call in case of an accident? |
 |
 |
taa nee eh ma Pay tee ee jaam baa baa seh leh? |
 |
Tani ẹ ma pè tì ìjàmbá bá ṣẹlẹ̀? |
 |
 |
Are there operational emergency vehicles here? |
 |
 |
shay awoH oo ko fU ee sheh leh Paa jaa wee ree tee ohn shee sheh waa? |
 |
Ṣé àwọn ọkọ̀ fún ìṣẹ̀lẹ̀ pàjáwírí tí ó nṣiṣẹ́ wà? |
 |
 |
How many telephones do you have in the area? |
 |
 |
telee foo no may loo nee o waa nee aBeBe yee? |
 |
Tẹlifónù mélo ni ó wà ní agbègbè yì í? |
 |
 |
How many homes have telephones here? |
 |
 |
ee lay may loo nee o nee telee foo no nee bee? |
 |
Ilé mélo ni ó ní tẹlifónù níbí? |
 |
 |
Is there a functioning police station? |
 |
 |
shay aa go o loo Paa tee ohn see sheh waa? |
 |
Ṣé àgọ́ ọlọ́ọ̀pá tí ó nṣiṣẹ́ wà? |
 |
 |
How many personnel are still on the job? |
 |
 |
awoH o see sheh may loo nee oo ko leh no ee sheh? |
 |
Àwọn òṣìṣẹ́ mélo ni ó kù l'ẹ́nu iṣẹ́? |
 |
 |
What's the means of communication? |
 |
 |
kee nee oo na ee baa nee so roo? |
 |
Kíni ònà ìbánisọ̀rọ̀? |
 |
 |
Can the police station function normally without U.S. assistance? |
 |
 |
shay aa go o loo Pa lay see sheh laa ee see ee roH loo wo awoH aa raa aamee ree ka? |
 |
Ṣé àgọ́ ọlọ́ọ̀pá lè ṣiṣẹ́ láìsí ìrànlọ́wọ́ àwọn ará Améríkà? |
 |
 |
Can U.S. forces depend on the local police to perform their duties as needed? |
 |
 |
shay awoH o loo gU aamee ree ka lay Baa raa lay awoH o loo Paa ee bee leh laa tee shay ee sheh woH day day? |
 |
Ṣé àwọn ológun Améríkà lè gbára lé àwọn ọlọ́ọ̀pá ìbílẹ láti ṣe iṣẹ́ nwọn dédé? |
 |
 |
How many vehicles are available? |
 |
 |
oo ko may loo nee o waa? |
 |
Ọkọ̀ mélo ni ó wà? |
 |
 |
What is the telephone number? |
 |
 |
kee nee nom baa telee foo no na? |
 |
Kíni nọ́múbà tẹlifónù náà? |
 |
 |
Do you use radio communications? |
 |
 |
shay eh ohn loo eh roo ray dee yo laa tee so roo? |
 |
Ṣé ẹ̀ nlo ẹ̀rọ rẹ́díò láti sọ̀rọ̀? |
 |