 |
Is there a medical facility nearby? |
 |
 |
shay ee lay ee wo saH waa nee to see? |
 |
Ṣé ilé ìwòsàn wà nítòsí? |
 |
 |
Are there any doctors in the area? |
 |
 |
shay awoH do kee ta waa nee aBeBe yee? |
 |
Ṣé àwọn dókítà wà ní agbègbè yì í? |
 |
 |
How many beds do you have at the medical facility? |
 |
 |
ee boo sU may loo nee eh nee nee lay ee wo saH na? |
 |
Ibùsùn mélo ni ẹ ní ní'lé ìwòsàn ná à? |
 |
 |
How many people work at the hospital? |
 |
 |
awoH o see sheh may loo nee ohn see sheh nee lay ee wo saH na? |
 |
Àwọn òṣìṣẹ́ mélo ni ó n ṣiṣẹ ní'lé ìwòsàn ná à? |
 |
 |
How many nurses? |
 |
 |
awoH no see may loo? |
 |
Àwọn nọ́ọ̀sì mélo? |
 |
 |
Has there been any infectious disease in the area lately? |
 |
 |
shay aa rU ko ko beh seh leh nee aBeBe yee lay Peh? |
 |
Ṣé ààrùn kankan bẹ́ sílẹ̀ ní agbègbè yì í láìpẹ́? |
 |
 |
Is there a pharmacy? |
 |
 |
shay ee lay eh Bo gee waa? |
 |
Ṣé ilé egbògi wà? |
 |
 |
Is there a building where we could set up a medical facility? |
 |
 |
shay ee lay tee a lay loo fU ee lay ee wo saH wa? |
 |
Ṣé ilé tí a lè lò fún ilé ìwòsàn wa? |
 |
 |
We would like to talk to people about immunization. |
 |
 |
a feh baa awoH eh nee yaH so roo nee Pa a beh reh a jeh saa raa |
 |
A fẹ́ bá àwọn ènìyàn sọ̀rọ̀ nípa abẹ́rẹ́ àjẹsára |
 |
 |
We would like to talk to people about sanitization. |
 |
 |
a feh baa awoH eh nee yaH so roo nee Pa taa nee yaa |
 |
A fẹ́ bá àwọn ènìyàn sọ̀rọ̀ nípa taniyá |
 |
 |
Is there a medical emergency facility? |
 |
 |
shay ee lay ee wo saH fU ee seh leh Paa jaa wee ree waa? |
 |
Ṣé ilé ìwòsàn fún ìṣẹ̀lẹ̀ pàjáwírí wà? |
 |
 |
We have to establish a safe working environment. |
 |
 |
a nee laa tee ree wee Pay ko say woo fU awoH o see sheh leh no ee sheh |
 |
A ní látí ri wípé kò s'ewu fún àwọn òṣìṣẹ́ l'ẹ́nu iṣẹ́ |
 |
 |
We have to hire medical doctors for this facility. |
 |
 |
a nee laa tee Ba awoH do kee ta fU ee bee yee |
 |
A ní látí gba àwọn dókítà fún ibí yì í |
 |
 |
We have to hire nurses for this facility. |
 |
 |
a nee laa tee Ba awoH no see fU ee bee yee |
 |
A ní látí gba àwọn nọ́ọ̀sì fún ibí yì í |
 |
 |
We have to hire office personnel for this facility. |
 |
 |
a nee laa tee Ba awoH o see sheh a ko way fU ee bee yee |
 |
A ní látí gba àwọn òṣìṣẹ́ akọ̀wé fún ibí yì í |
 |
 |
We have to hire a custodian for this facility. |
 |
 |
a nee laa tee Ba o loo bo jo to fU ee bee yee |
 |
A ní látí gba olùbójútó fún ibí yì í |
 |
 |
Are the local facilities and personnel able to care for the current casualties without U.S. aid? |
 |
 |
shay awoH o shee sheh a tee ee lay ee wo saH ee bee leh lay to jo awoH tee o tee nee ee Pi nee no ee shee leh laa ee see ee roH loo wo awoH aa raa aamee ree ka? |
 |
Ṣé àwọn òṣìṣẹ́ àti ilé ìwòsàn ìbílẹ̀ lè tọ́jú àwọn tí ó ti ní ìpín nínú ìṣẹ̀lẹ̀ láìsí ìrànlọ́wọ́ àwọn ará Améríkà? |
 |
 |
Is the local drinking water potable? |
 |
 |
shay o mee mee moo ee bee leh daa ra? |
 |
Ṣé omi mímu ìbílẹ̀ dára? |
 |
 |
Who determined that the water is potable? |
 |
 |
taa nee o waa dee wee Pay o mee mee moo na daa raa? |
 |
Tani ó wáàdí wípé omi mímu ná à dára? |
 |