Get Instructions
main picture
Title Bar
Go To Main Menu Print Page previous page PagePage Total next page
Play Button Who is in charge of repairing roads? Play Button taa nee o waa nee dee tee tU oo na shay? Tani ó wà n'ìdí títún ọ̀nà ṣe?
Play Button Do you have a map of this area? Play Button shay o nee aa wo roH ee to nee so no fU aBeBe yee? Ṣe o ní àwòrán ìtọ́nisọ́nà fún agbègbè yì í?
Play Button We will provide assistance in building roads at this location. Play Button a maa Pay say ee roH loo wo fU oo na see shay nee aBeBe yee A má a pèsè ìrànlọ́wọ́ fún ọ̀nà ṣíṣe ní agbègbè yì í
Play Button Can you provide a road map of this area? Play Button shay o lay Pay say a wo roH ee to nee so no fU aBeBe yee? Ṣe o lè pèsè àwòrán ìtọ́nisọ́nà fún agbègbè yì í?
Play Button Do you have any machinery for road building? Play Button shay o nee ee rE seh ko ko fU oo na see shay? Ṣe o ní irinṣẹ́ kankan fún ọ̀nà ṣíṣe?
Play Button Do you have any machinery for road repairs? Play Button shay o nee ee rE seh ko ko fU tee tU oo na shay? Ṣe o ní irinṣẹ́ kankan fún títún ọ̀nà ṣe?
Play Button We have to set up storage locations for supply materials in the area. Play Button a nee laa tee shay ee to ee bee tee awoH ohn eh loo yo waa nee aBeBe yee A ní láti ṣe ètò ibi tí àwọn ohun èlò yíò wà ní agbègbè yì í
Play Button Are there any railroad tracks in this area? Play Button shay o jo ee rE ko ko waa nee aBeBe yee? Ṣé ojú irin kankan wà ní agbègbè yì í?
Play Button Do you have transportation facilities in this area? Play Button shay eh nee eh to oo ko fU awoH aa raa aBeBe yee? Ṣé ẹ ní ètò ọkọ̀ fún àwọn ará agbègbè yì í?
Play Button Are there any airports nearby? Play Button shay ee boo Beh oo ko baa loo waa nee to see? Ṣé ibùgbé ọkọ̀ bàálù wà nítòsì?
Play Button Are there any landing fields for smaller aircraft nearby? Play Button shay Pa Pa oo ko baa loo kay kay ray ko ko waa nee to see? Ṣé pápá ọkọ̀ bàálù kékeré kankan wà nítòsì?
Play Button Are there any pipelines in the area? Play Button shay Paay Pu laa nE ko ko waa nee aBeBe yee? Ṣé páìpùlaìnì kankan wà ní agbègbè yì í?
Play Button Is the pipeline fenced off in this area? Play Button shay woH shay o Baa fU Paay Pu laa nE nee aBeBe yee? Ṣé nwọ́n ṣe ọgbà fún páìpùlaìnì ní agbègbè yì í?
Play Button Is the traffic heavy in this area? Play Button shay go sloo maa ohn Poh nee aBeBe yee? Ṣé gó silò ma n pọ̀ ní agbègbè yì í?
Play Button Are there bus lines or trains to travel to other places? Play Button shay oo ko a jaa Be taa bee oo ko o jo ee rE waa laa tee loo ee rE aa jo wa? Ṣé ọkọ̀ àjàgbè tàbí ọkọ̀ ojú irin wà láti lọ ìrìnàjò wà?
Play Button Are there taxis? Play Button shay awoH oo ko ta kee see waa? Ṣé àwọn ọkọ̀ takisí wà?
Play Button Do these roads get snowed in during the winter? Play Button shay o jo yee yee maa ohn roo bo awoH oo na yee nee Ba o too too o yee bo? Ṣe òjò yìnyín má a n rọ̀ bo àwọn ọ̀nà yì í ní'gbà òtútù òyìnbó?
Play Button How many people own motor vehicles in this area? Play Button awoH may loo nee woH nee oo ko nee aBeBe yee? Àwọn méèló ni nwọ́n ní ọkọ̀ ní agbègbè yì í?
Play Button Are there trucking companies nearby? Play Button shay awoH o nee sho wo oo ko ohn laa waa nee to see? Ṣé àwọn oníṣòwò ọkọ̀ n'lá wà nítòsì?
Play Button Do you have radio contact with people in other places? Play Button shay o nee eh roo ray dee yo tee o fee ohn ba awoH aa raa ee bo mee raa so roo? Ṣé o ní ẹ̀rọ rẹ́díò tí o fi n bá àwọn ará ibòmíràn s'ọ̀rọ̀?
Play Button Can you use these roads during the winter? Play Button shay eh lay loo awoH oo na yee tee o jo yee yee baa ohn roo nee Ba o too too o yee bo? Ṣe ẹ lè lo àwọn ọ̀nà yì í tí òjò yìnyín bá nrọ̀ ní'gbà òtútù òyìnbó?
Go To Main Menu Print Page DLIFLC 2007 previous page PagePage Total next page