|
|
|
Do not stop if the convoy is attacked! |
|
|
maa shay do roo tee woH ba dee gU loo awoH oo ko ee rE aa jo wa! |
|
Má ṣe dúró ti nwọ́n bá di'gun lù àwọn ọkọ̀ ìrìnàjò wa! |
|
|
Drive a minimum of 3 kms before stopping. |
|
|
wa oo ko fU, o kay ray jo, kee loo mee ta mey ta kee o to do roo |
|
Wa ọkọ̀ fún, ókéréjù, kìlómítà mẹ́ta kí o tó dúró |
|
|
Following distance is 100m on open highway. |
|
|
a yeh o go rU mee ta nee see sheh ohn tel lay jeh nee Po Po tee tee ma roo seh |
|
Àyè ọgọ́rùn mítà ni ṣísẹ̀ n tẹ̀lé jẹ́ ní pópó títì márosẹ̀ |
|
|
Following distance is 50m in towns. |
|
|
a yeh a doo ta mee taa nee see sheh in tel lay jeh nee awoH aa rE ee loo |
|
Àyè àádọ́ta mítà ni ṣísẹ̀ n tẹ̀lé jẹ́ ní àwọn àárín ìlú |
|
|
When stopped on the road, keep enough space between vehicles to drive around if required. |
|
|
tee ee woH baa daa yee do roo, eh fee a yee Poo Po see leh laa rE awoH oo ko kee eh lay Ba eh Beh tee eh baa feh |
|
Tí nwọ́n bá dá yín dúró, ẹ fi àyè púpọ̀ s'ílẹ̀ láàrín àwọn ọkọ́ kí ẹ lè gba ẹ̀gbẹ́ tí ẹ bá fẹ́ |
|
|
If you lose sight of the convoy, slow down and wait for a military truck to pass you, and follow it. |
|
|
tee eh ko ba ree awoH oo ko ee rE a jo yee nee waa jo mo, eh roo ra maa loo, kee eh see do roo tee tee oo ko o loo gU ohn laa maa fee ko jaa, kee eh see teh lay |
|
Tí ẹ kò bá rí àwọn ọkọ̀ ìrìnàjò yín níwájú mọ́, ẹ rọra má a lọ, kí ẹ sì dúró títí ọkọ̀ ológun nlá fi kọjá, kí ẹ sì tẹ̀le |
|
|
No weapons. |
|
|
ko see awoH ohn ee jaa |
|
Kò sí àwọn ohun ìjà |
|
|
No cell phone use. |
|
|
maa shay loo telee fo no oo wo |
|
Má ṣe lo tẹlifóònù ọwọ́ |
|
|
Do not throw food or water to the locals. |
|
|
maa shay jo on jeh taa bee o mee see awoH aa raa ee loo |
|
Má ṣe ju oúnjẹ tàbí omi sí àwọn ará ìlú |
|
|
No littering or dumping trash on military camps or staging areas. |
|
|
maa shay jo ee doo tay taa bee da ee leh see ee boo do taa bee saa kaa nee awoH o loo gU |
|
Má ṣe ju ìdọ̀tí tàbí da ilẹ̀ sí ibùdó tàbí sàkání àwọn ológun |
|
|
Go around any broken down truck in the convoy. |
|
|
Ba eh Beh ey yee kay yee oo ko ohn laa tee o ba tee da koo nee no awoH oo ko ee rE ha jo yee |
|
Gba ẹ̀gbẹ́ èyíkéyí ọkọ́ nlá tí ó bá ti dákú nínú àwọn ọkọ̀ ìrìnàjò yín |
|
|
No flashing beacons. |
|
|
ee na toH na toH na |
|
Iná tanná tanná |
|
|
Fuel vehicle every time vehicle stops. |
|
|
roo eh Po see oo ko nee Bo Bo ee Baa tee oo ko baa tee do roo |
|
Rọ epo sí ọkọ́ ní gbogbo ìgbà tí ọkọ́ bá ti dúró |
|
|
Food is provided at some military camps when available. |
|
|
woH maa ohn Pay say on jeh nee ee boo do awoH o loo gU tee on jeh ba waa |
|
Nwọ́n ma n pèsè oúnjẹ ní ibùdó àwọn ológun tí oúnjẹ ba wà |
|
|
Bring plenty of food and water with you. |
|
|
Beh on jeh aa tee o mee Po Po daa nee |
|
Gbé oúnjẹ àti omi púpọ̀ dání |
|
|
If you have to stop for any reason and the convoy continues, wait for help from the military. |
|
|
tee o baa nee laa tee do roo fU on ko ohn, tee awoH oo ko ee rE aa jo yee see ohn loo nee wa jo, do roo fU ee roH loo wo awoH o loo gU |
|
Tí o bá ní láti dúró fún ohun kóun, tí àwọn ọkọ̀ ìrìnàjò yín sì nlọ níwájú, dúró fún ìrànlọ́wọ́ àwọn ológun |
|
|
They will escort you back into position. |
|
|
woH maa see eh Pa da see ee Po |
|
Nwọ́n ma sìn ẹ́ padà sí ipò |
|
|
No fighting or arguing with any other driver over position in convoy. |
|
|
maa shay jaa taa bee jee ya Pah loo aa wa ko ko ko nee Pa ee Po reh laa rE awoH oo ko ee rey aa jo yee |
|
Má ṣe jà tàbí jiyàn pẹ̀lú awakọ̀ kankan nípa ipò rẹ láàrin àwọn ọkọ̀ ìrìnàjò yín |
|
|
Drive in a single file. |
|
|
wa oo ko loo ree ee laa ko so so |
|
Wa ọkọ̀ l'órí ìlà kan ṣoṣo |
|
|
Be prepared to stop and assist broken down trucks. (Note: This is an instruction for bobtail drivers.) |
|
|
moo raa laa tee do roo kee o lay roH oo ko ohn laa tee oo ba tee daa koo loo wo (mo weh Peh: ee mo roH yee wa fU awoH aa wa ko o loo Po) |
|
Múra láti dúró kí o lè ran ọkọ́ nlá tí ó bá ti dákú l'ọ́wọ́ (Mọ̀ wípé: Ìmọ̀ràn yí wà fún àwọn awakọ̀ ọlọ́pọ́n) |
|
|
Report any problems with other drivers to the convoy commander. |
|
|
fee eh soo wa ha laa Peh loo aa wa ko ko ko soo o loo daa ree awoH oo ko ee rE ya jo yee |
|
Fi ẹ̀sùn wàhálà pẹ̀lú awakọ̀ kankan sun olùdarí àwọn ọkọ̀ ìrìnàjò yín |
|
|
No drug or alcohol use while driving. |
|
|
maa shay moo o gU o loo roo taa bee o tee tee o baa ohn wa oo ko |
|
Má ṣe mu oògùn olóró tàbí ọtí tí o bá n wa ọkọ̀ |
|
|
Know how to change tires and have proper tools. |
|
|
mo bee o tee maa Pa roo awoH taa yaa kee o see nee ee rE seh gee dee loo wo |
|
Mọ̀ bí o ti ma pàrọ̀ àwọn táyà kí o sì ní irinṣẹ́ gidi lọ́wọ́ |
|
|
Loads, straps, chains, and tires are the drivers' responsibility. |
|
|
awoH eh roo, oo kU, shay nee, aa tee taa yaa jeh ohn ko ee bo jo to fU awoH aa wa ko |
|
Àwọn erù, okùn, ṣéènì, àti táyà jẹ́ nkan ìbójútó fún àwọn awakọ̀ |
|
|
Check every time the convoy stops. |
|
|
shay aa yeh wo nee Bo Bo ee Baa tee awoH oo ko ee rey aa jo yee baa do roo |
|
Ṣe àyèwò ní gbogbo ìgbà tí àwọn ọkọ̀ ìrìnàjò yín bá dúró |
|
|
|
|