 |
How many people live in this area? |
 |
 |
eh nee may loo nee ohn Beh nee aBeBe yee? |
 |
Eni mélo ni ó ngbé ní agbègbè yì í? |
 |
 |
How many water wells do you have in this area? |
 |
 |
ko ga o mee may loo nee o wa nee aBeBe yee? |
 |
Kànga omi mélo ni ó wà ní agbègbè yì í? |
 |
 |
Do you have a sewage system in this area? |
 |
 |
shay eh nee eh to fU aa kee tee ya eh roo o mee ee doo tee aa tee mee moo nee aBeBe yee? |
 |
Ṣé ẹ ní ètò fún akitiyan ẹ̀rọ omi ìdọ̀tí àti mímu ní agbègbè yì í? |
 |
 |
How far are the latrines from the water wells? |
 |
 |
baa wo nee awoH saa laan gaa shay jee na see awoH ko ga o mee? |
 |
Báwo ni àwọn ṣálángá ṣe jìnà sí àwọn kànga omi? |
 |
 |
What type of herds graze in this area? |
 |
 |
awoH eh ro ko wo nee o maa ohn jeh ko nee aBeBe yee? |
 |
Àwọn ẹranko wo ni ó ma n jẹ'ko ní agbègbè yì í? |
 |
 |
Is there a veterinarian? |
 |
 |
shay o loo wo so fU awoH eh roH ko waa? |
 |
Ṣé olùwòsàn fún àwọn ẹranko wà? |
 |
 |
Are there any factories in the area? |
 |
 |
shay awoH ee lay ee sheh ko ko waa nee aBeBe yee? |
 |
Ṣé àwọn ilé iṣẹ́ kankan wà ní agbègbè yì í? |
 |
 |
Is there a river nearby? |
 |
 |
shay o do waa nee to see? |
 |
Ṣé odò wà nítòsí? |
 |
 |
Where do you get electricity from? |
 |
 |
ee bo nee ee na yee tee ohn waa? |
 |
Ibo ni iná yín ti n wá? |
 |
 |
Is there a power plant nearby? |
 |
 |
shay ee lay ee sheh ee na waa nee to see? |
 |
Ṣé ilé iṣẹ́ iná wà nítòsí? |
 |
 |
What kind of electrical appliances do people use? |
 |
 |
ee roo ohn ko eh roo wo nee awoH eh nee ya nee tee ohn loo ee na? |
 |
Irú nkan ẹ̀rọ wo ni àwọn ènìyàn ní tí ó nlo iná? |
 |
 |
Do you use electric stoves? |
 |
 |
shay eh maa ohn loo awoH on ee daa na tee ohn loo ee na? |
 |
Ṣé ẹ ma nlo àwọn ohun ìdáná tí ó nlo iná? |
 |
 |
Have there been forest fires in the area? |
 |
 |
shay awoH oo ko tee day day Ba na nee aBeBe yee ree? |
 |
Ṣé àwọn oko ti dédé gbaná ní agbègbè yì í rí? |
 |
 |
Are there any gas pipes around here? |
 |
 |
shay Paay Poo gaa see ko ko waa nee aBeBe yee? |
 |
Ṣé páìpù gáàsì kankan wà ní agbègbè yì í? |
 |
 |
Do you use gas to heat homes around here? |
 |
 |
shay eh maa ohn loo gaa see laa tee Bo na ee lay nee aBeBe yee? |
 |
Ṣé ẹ ma nlo gáàsì láti gbóná ilé ní agbègbè yì í? |
 |
 |
Is gas used for cooking? |
 |
 |
shay eh maa ohn loo gaa see laa tee shay on jeh? |
 |
Ṣé ẹ ma nlo gáàsì láti se oúnjẹ? |
 |
 |
Do you use propane gas tanks? |
 |
 |
shay eh maa ohn loo taan kee gaa see? |
 |
Ṣé ẹ ma nlo táànkì gáàsì? |
 |
 |
Where do you get propane gas tanks supplied from? |
 |
 |
ee bo nee woH tee ohn ko taan kee gaa see yee waa? |
 |
Ibo ni nwọ́n ti nkó táànkì gáàsì yín wá? |
 |
 |
Is there anyone to inspect home gas appliances? |
 |
 |
shay eh nee ya wa fU ee beh wo gaa see lee loo nee lay? |
 |
Ṣé ènìyàn wà fún ìbẹ̀wò gáàsì lílò nílé? |
 |
 |
Is there an electrician here? |
 |
 |
shay eh nee tee ohn shay ee na waa? |
 |
Ṣé ẹni tí ó nṣe iná wà? |
 |
 |
Is there a water supply system to households? |
 |
 |
shay eh nee eh to o mee fU awoH o nee lay aBeBe yee? |
 |
Ṣé ẹ ní ètò omi fún àwọn onílé agbègbè yì í? |
 |
 |
Where is the facility located? |
 |
 |
ee bo nee ee lay ee sheh na waa? |
 |
Ibo ni ilé iṣẹ́ ná à wá? |
 |
 |
How many people operate the system? |
 |
 |
eh nee may loo nee ohn shee seh loo ree eh roo na? |
 |
Eni méèlo ni ó nṣiṣẹ́ l'órí ẹ̀rọ ná à? |
 |
 |
Is it connected to other water supply systems? |
 |
 |
shay o jaa mo awoH o mee eh roo mee roH? |
 |
Ṣé ó já mọ́ àwọn omi ẹ̀rọ mìràn? |
 |
 |
Is it functional? |
 |
 |
shay ohn shee sheh? |
 |
Ṣé ó nṣiṣẹ? |
 |
 |
Is it by sedimentation? |
 |
 |
shay woH jeh ko gU nee? |
 |
Ṣé nwọ́n jẹ́ kó gún ni? |
 |
 |
Where is the pumping station? |
 |
 |
ee bo nee a go o mee fee faa waa? |
 |
Ibo ni àgọ́ omi fífà wà? |
 |
 |
How many people are needed to keep the system functional? |
 |
 |
eh nee may loo nee o lay jeh kee ee sheh maa loo day day? |
 |
Ẹni méèló ni ó lè jẹ́ kí iṣẹ́ má a lọ dédé? |
 |
 |
We've heard that there have been some problems with sewage in this neighborhood. |
 |
 |
a tee Bo nee Pa awoH waa ha laa Peh loo eh to o mee aa tee ee doo tee nee aa do Bo yee |
 |
A ti gbọ́ nípa àwọn wàhálà pẹ̀lú ètò omi àti ìdọ̀tí ní àdúgbò yì í |
 |
 |
Do you have indoor plumbing? |
 |
 |
shay eh nee Paa ee Po o mee eh roo nee no ee lay? |
 |
Ṣé ẹ ní páìpù omi ẹ̀rọ nínú ilé? |
 |
 |
Do you have any problems with your plumbing? |
 |
 |
shay eh nee waa ha laa Peh loo Paa ee Po o mee eh roo nee no ee lay? |
 |
Ṣé ẹ ní wàhálà pẹ̀lú páìpù omi ẹ̀rọ nínú ilé? |
 |
 |
Does your toilet work? |
 |
 |
shay ee lay ee Bo seh yee ohn shee sheh? |
 |
Ṣé ilé ìgbọ̀nsẹ̀ yín n ṣiṣẹ́? |
 |
 |
How many toilets do you have in the house? |
 |
 |
ee lay ee Bo see may loo nee eh nee nee no ee lay? |
 |
Ilé ìgbọ̀nsẹ̀ méèló ni ẹ ní nínú ilé? |
 |
 |
Do you have a septic tank? |
 |
 |
shay eh nee so kaa way? |
 |
Ṣé ẹ ní sọ́kàwéè? |
 |
 |
Is there anyone who can fix your sewer? |
 |
 |
shay eh nee eh nee ya tee o maa ohn toon sho kaa way shay? |
 |
Ṣé ẹ ní ènìyàn tí ó ma n tún sọ́kàwéè ṣe? |
 |
 |
Have you contacted anyone regarding this problem? If so who? |
 |
 |
shay eh tee so fU eh nee ka nee nee Pa wa ha laa yee? tee o ba jeh beh, taa nee? |
 |
Ṣé ẹ ti sọ fún ẹnikẹ́ni nípa wàhálà yì í? Tí ó bá jẹ́ bẹ̀, tani? |
 |
 |
When did you contact them? |
 |
 |
ee Baa wo nee eh so fU woH? |
 |
Ìgbàwo ni ẹ sọ fún nwọn? |
 |
 |
I will report this higher up and see if there is something we can do to fix the sewage problem. |
 |
 |
maa aa so fU awoH o ga bo ya aa lay ree ohn ko shay nee Pa wa ha laa so kaa way yee |
 |
Mà á sọ fún àwọn ọ̀gá bóyá a lè rí n kan ṣe nípa wàhálà sọ́kàwéè yì í |
 |
 |
We will contact the sewage company and find out what is being done to correct the problem. |
 |
 |
a Pay ee lay ee sheh awoH oo nee so kaa way laa tee wa dee ohn ko tee woH ohn shay nee Pa wa ha laa yee |
 |
À á pe ilé iṣẹ àwọn oní sọ́kàwéè láti wáàdí nkan tí nwọ́n nṣe nípa wàhálà yì í |
 |