 |
How many radios and TVs are in this area? |
 |
 |
eh roo a Bo hU maa Bay see a tee a mo hU maa wo roH may loo nee o waa nee aBeBe yee? |
 |
Ẹrọ agbọ́hùn-mágbèsì àti amọ́hùn-máwòrán méèló ni ó wà ní agbègbè yì í? |
 |
 |
Do you have a radio station in this area? |
 |
 |
shay eh nee eh leh eh roo a Bo aa Beh see nee aBeBe yee? |
 |
Ṣé ẹ ní ilé ẹ̀rọ agbọ́hùn-mágbèsì ní agbègbè yì í? |
 |
 |
Do you have a TV station in the area? |
 |
 |
shay eh nee eh leh eh roo a mo maa wo roH nee aBeBe yee? |
 |
Ṣé ẹ ní ilé ẹ̀rọ amọ́hùn-máwòrán ní agbègbè yì í? |
 |
 |
Do you have a public announcement system? |
 |
 |
shay eh nee eh to ee Po loon go fU awoH aa raa ee loo? |
 |
Ṣé ẹ ní ètò ìpolongo fún àwọn ará ìlú? |
 |
 |
Where do you post announcements? |
 |
 |
ee bo nee eh teen shay ee Po loon go fU awoH aa raa ee loo? |
 |
Ibo ni ẹ tí n ṣe ìpolongo fún àwọn ará ìlú? |
 |
 |
Is there a local newspaper? |
 |
 |
shay ee way ee roo hee ee bee leh waa? |
 |
Ṣé ìwé ìròhìn ìbílẹ̀ wà? |
 |
 |
Is there a news agency representative nearby? |
 |
 |
shay a so jo awoH ee roo hee waa nee to see? |
 |
Ṣé aṣoojú àwọn ìròhìn wà nítòsí? |
 |
 |
Is there an information center? |
 |
 |
shay ee bee ee Po loon go waa? |
 |
Ṣé ibi ìpolongo wà? |
 |
 |
Do you receive fliers? |
 |
 |
shay eh maa ohn Ba awoH ee way ee Po loon go Pen bay lay? |
 |
Ṣé ẹ má a n gba àwọn ìwé ìpolongo pénbélé? |
 |
 |
Who distribute the fliers? |
 |
 |
taa nee o maa ohn Pi awoH ee way ee Po loon go Pen bay lay? |
 |
Ta ni ó ma n pín àwọn ìwé ìpolongo pénbélé? |
 |