 |
Who now occupies your farm? |
 |
 |
taa nee o wa nee o ree oo ko reh baa yee? |
 |
Tani ó wà ní orí oko rẹ báàyí? |
 |
 |
Have you talked with them? |
 |
 |
shay o tee baa woH so roo? |
 |
Ṣe o ti bá nwọ́n sọ̀rọ̀? |
 |
 |
Do you have documentation? |
 |
 |
shay o nee ee way eh ree? |
 |
Ṣe o ní ìwé ẹ̀rí? |
 |
 |
Do you think it's dangerous? |
 |
 |
shay o roo wee Pay o lay woo? |
 |
Ṣe o rò wípé ó l'ewu? |
 |
 |
I will contact the appropriate authorities to investigate this matter. |
 |
 |
maa a so fU awoH ee jo ba kee woH shay ee waa dee oo roo yee |
 |
Mà á sọ fún àwọn ìjọba kí nwọ́n ṣe ìwáàdí ọ̀rọ̀ yì í |
 |
 |
Please know we will assist you. |
 |
 |
jo wo mo wee Pay a maa roH eh loo wo |
 |
Jọ̀wọ́ mọ̀ wípé a ma ràn ẹ́ lọ́wọ́ |
 |
 |
You must allow the local authorities to conduct their investigation. |
 |
 |
on laa tee jeh kee awoH ee jo ba shay ee waa dee woh |
 |
Òún láti jẹ́ kí àwọn ìjọba ṣe ìwáàdí nwọ́n |
 |
 |
You must go to the base and speak with an interpreter. |
 |
 |
on laa tee loo see ee boo do kee o ba o loo too mo so roo |
 |
Òún láti lọ sí ibùdó kí o bá olùtumọ̀ sọ̀rọ̀ |
 |
 |
The name of the owner |
 |
 |
daa roo ko oo nee ohn ko |
 |
Dárúkọ oní nkan |
 |
 |
The name of the property |
 |
 |
oo roo ko on ee nee na |
 |
Orúkọ ohun ìní ná à |
 |
 |
Location of the property |
 |
 |
ee bee tee ohn ee nee na waa |
 |
Ibi tí ohun ìní ná à wà |
 |
 |
Present use of the property |
 |
 |
ee loo ohn ee nee na nee a koko yee |
 |
Ìlò ohun ìní ná à ní àkokò yì í |
 |
 |
What is the condition of the property? |
 |
 |
ee Po wo nee ohn ee nee na waa? |
 |
Ipò wo ni ohun ìní ná à wà? |
 |
 |
Who has the title? |
 |
 |
taa nee oo nee ee way eh ree ohn ee nee? |
 |
Tani ó ní ìwé ẹ̀rí ohun ìní? |
 |