|
May I see your ID, please? |
|
|
jo wo shay mo lay ree ee way ee daa nee mo reh? |
|
Jọ̀wọ́ ṣé mo lè rí ìwé ìdánimọ̀ rẹ? |
|
|
Where are you going? |
|
|
ee bo loon loo? |
|
Ibo lò n lọ? |
|
|
Are you carrying any weapons? |
|
|
shay o Beh ohn ko ee jaa daa nee? |
|
Ṣé o gbé nkan ìjà dání? |
|
|
How much money are you carrying? |
|
|
eh loo nee oo wo tee oo Beh daa nee? |
|
Èló ni owó tí o gbé dání? |
|
|
Who gave you the money? |
|
|
taa nee oo fU eh loo wo na? |
|
Tani ó fún ẹ l'owó ná à? |
|
|
Do you have a gun under the seat? |
|
|
shay oo nee ee bo nee aa beh ee jo ko? |
|
Ṣé o ní ìbọn ní abẹ́ ìjóko? |
|
|
Are you hiding anything illegal? |
|
|
shay on Beh ohn ko tee oo loo dee so fee Pa mo? |
|
Ṣé o n gbé nkan tí ó lòdì s'ófin pamọ́? |
|
|
Since you broke the law, we have to arrest you. |
|
|
nee to ree oo tee loo dee so fee, aa nee laa tee moo eh |
|
Nítorí o ti lòdì s'òfin, a ní láti mú ẹ |
|
|
We have to take you to the police station. |
|
|
a nee laa tee moo eh loo see aa go o loo Paa |
|
A ní láti mú ẹ lọ sí àgọ́ ọlọ́ọ̀pà |
|
|
You will ride with us to the police station. |
|
|
waa teh lay wa nee no oo ko loo see aa go o loo Paa |
|
Wà á tẹ̀lé wa nínú ọkọ̀ lọ sí àgọ́ ọlọ́pà |
|