 |
Do you have pain in this joint I'm touching? |
 |
 |
sheh ee bee ee gU tee mo ohn fee o wo ko yee ohn dU eh? |
 |
Ṣé ibi igun tí mo n fi ọwọ́ kàn yì í n dùn ẹ́? |
 |
 |
Do you have pain in any other joint? |
 |
 |
sheh ee bee ee gU meeraH ohn dU eh? |
 |
Ṣé ibi igun mìíràn n dùn ẹ́? |
 |
 |
Which joint hurts the most? |
 |
 |
ee bee ee gU wo nee ohn dU eh jo? |
 |
Ibi igun wo ni o n dùn ẹ́ jù? |
 |
 |
Do you have pain in this muscle I'm touching? |
 |
 |
sheh ee bee ee sho tee mo ohn fee o wo ko yee ohn dU eh? |
 |
Ṣé ibi iṣan tí mo n fi ọwọ́ kàn yì í n dùn ẹ́? |
 |
 |
Do you have pain in any other muscle? |
 |
 |
sheh ee bee ee sho meeraH ohn dU eh? |
 |
Ṣé ibi iṣan mìíràn n dùn ẹ́? |
 |
 |
Where is the muscle pain? |
 |
 |
ee bo nee ee roo raa ee sho no waa? |
 |
Ibo ni ìrora iṣan ná à wà? |
 |
 |
Is this muscle cramping? |
 |
 |
sheh ee roo raa ee sho no ohn moo eh? |
 |
Ṣé ìrora iṣan ná à n mú ẹ? |
 |
 |
Have you ever had any broken bones? |
 |
 |
sheh eh gU gU reh tee ko ree? |
 |
Ṣé egungun rẹ ti kán rí? |
 |
 |
What bones have you broken? |
 |
 |
awoH eh gU gU wo loo tee ko ree? |
 |
Àwọn egungun wo ló ti kán rí? |
 |
 |
Does it hurt when I do this? |
 |
 |
sheh ohn dU eh tee mo baa sheh baa yee? |
 |
Ṣé ó n dùn ẹ́ tí mo bá ṣe báàyí? |
 |
 |
Do this. |
 |
 |
sheh baa yee |
 |
Ṣe báàyí |
 |
 |
You need an X-ray of your bone. |
 |
 |
a nee laa tee ya fo to ee no eh gU gU eh |
 |
A ní láti ya fọ́tò inú egungun ẹ |
 |
 |
I will examine the X-ray and tell you what I see. |
 |
 |
maa shay a baa wo fo to ee no eh gU gU no, maa see so ohn ko tee mo ree fU eh |
 |
Mà á ṣe àbẹ̀wò fọ́tò inú egungun ná à, mà á sì sọ nkan tí mo rí fún ẹ |
 |
 |
The bone is broken here. |
 |
 |
eh gU gU no tee ko |
 |
Egungun ná à ti kán |
 |
 |
The bone is not broken here. |
 |
 |
eh gU gU no ko ko nee bee |
 |
Egungun ná à kò kán níbí |
 |
 |
You need a cast to help the bone heal. |
 |
 |
a ma Beh see no pee o pee kee eh gU gU no lay jee no |
 |
A ma gbe sínu Píopì kí egungun ná à lè jiná |
 |
 |
Do not remove the cast. |
 |
 |
maa shay yoo pee o pee no |
 |
Mà á ṣe yọ Píopì ná à |
 |
 |
Do not get the cast wet. |
 |
 |
maa shay jeh kee pee o pee no to to |
 |
Mà á ṣe jẹ́ kí Píopì ná à tutù |
 |
 |
You need a splint to help the injury heal. |
 |
 |
a ma fee ohn ko Beh do roo kee o lay jee no |
 |
A ma fi nkan gbé dúró kí ó lè jiná |
 |
 |
You may take the splint off to clean yourself. |
 |
 |
o lay yoo ohn ko tee a fee Beh eh seh eh do roo kee o lay no aa raa eh |
 |
O lè yọ nkan tí a fi gbé ẹsẹ̀ ẹ dúró kí o lè nu ara ẹ |
 |
 |
The splint must be replaced after you have cleaned yourself. |
 |
 |
a ma fee ohn ko tU tU Beh eh seh eh do roo tee o baa no aa raa eh taH |
 |
A ma fi nkan tuntun gbé ẹsẹ̀ ẹ dúró tí o bá nu ara ẹ tán |
 |
 |
You need a metal plate and screws to help the healing of your bone. |
 |
 |
a ma fee ee rE a tee ee sho moo woH Po kee eh gU gU eh lay jee no |
 |
A ma fi irin àti ìṣó mú nwọn pọ̀ kí egungun ẹ lè jiná |
 |
 |
We need to take you to the Operating Room to perform an operation on you. |
 |
 |
a nee laa tee Beh eh lo see tee aa ta o Poo ray sho no laa tee lo sheh o Poo ray sho no fU eh |
 |
A ní láti gbé ẹ lọ sí tíátà opuréṣọ̀nù láti lọ ṣe opuréṣọ̀nù fún ẹ |
 |