 |
When was your last period? |
 |
 |
ee Baa wo nee o sheh ohn ko o sho Beh hE? |
 |
Ìgbà wo ni o ṣe nkan oṣù gbẹ̀hìn? |
 |
 |
How many pregnancies have you had? |
 |
 |
o yU may lo nee o tee nee? |
 |
Oyún méèló ni o ti ní? |
 |
 |
Are you having any vaginal discharge? |
 |
 |
sheh o mee ko ko yoo nee no ee dee eh? |
 |
Ṣé omi kankan yọ nínú ìdí ẹ? |
 |
 |
Are you having vaginal bleeding? |
 |
 |
sheh eh jeh ohn yoo nee no ee dee eh? |
 |
Ṣé ẹ̀jẹ̀ n yọ nínú ìdí ẹ? |
 |
 |
How long have you had vaginal bleeding? |
 |
 |
ee Baa wo nee eh jeh tee ohn yoo nee no ee dee eh? |
 |
Ìgbà wo ni ẹ̀jẹ̀ ti n yọ nínú ìdí ẹ? |
 |
 |
Does the vaginal bleeding come and go? |
 |
 |
sheh eh jeh tee o ohn yoo nee no ee dee eh, o ohn wa, o ohn lo? |
 |
Ṣé ẹ̀jẹ̀ ti ó n yọ nínú ìdí ẹ ó n wá, ó n lọ? |
 |
 |
Is the vaginal bleeding constant? |
 |
 |
sheh eh jeh tee o ohn yoo nee no ee dee eh ko daa do roo? |
 |
Ṣé ẹ̀jẹ̀ ti ó n yọ nínú ìdí ẹ kò dá dúró? |
 |
 |
Do you feel dizzy? |
 |
 |
sheh o yee ohn ko eh? |
 |
Ṣé òyì n kọ́ ẹ? |
 |
 |
How many months have you been pregnant? |
 |
 |
o sho may lo nee o tee lo yoo? |
 |
Oṣù méèló ni o ti l'óyún? |
 |
 |
How many children do you have? |
 |
 |
o mo may lo lo nee? |
 |
Ọmọ méèló lo ní? |
 |