 |
Let us examine your child in private. |
 |
 |
jeh kee a sheh a beh wo o mo reh nee ko roo |
 |
Jẹ́ kí a ṣe àbẹ̀wò ọmọ rẹ ní kọ̀rọ̀ |
 |
 |
Your child will get better soon. |
 |
 |
aa raa o mo reh a daa laa ee Peh |
 |
Ara ọmọ rẹ á dá láìpẹ́ |
 |
 |
This medicine will help your child. |
 |
 |
eh Bo gee yee a raH o mo reh lo wo |
 |
Egbògi yì í á ran ọmọ rẹ l'ọ́wọ́ |
 |
 |
Did your child eat today? |
 |
 |
sheh o mo reh jeh ohn lay nee? |
 |
Ṣé ọmọ rẹ jẹun l'ènì? |
 |
 |
Did your child eat yesterday? |
 |
 |
sheh o mo reh jeh ohn laa no? |
 |
Ṣé ọmọ rẹ jẹun l'àná? |
 |
 |
Has your child passed urine today? |
 |
 |
sheh o mo reh tee to lay nee? |
 |
Ṣé ọmọ rẹ ti tọ̀ l'ènì? |
 |
 |
Has your child passed any stool today? |
 |
 |
sheh o mo reh tee ya Beh ko ko lay nee? |
 |
Ṣé ọmọ rẹ ti yà'gbẹ́ kankan l'ènì? |
 |
 |
Did your child pass any stool yesterday? |
 |
 |
sheh o mo reh yaa Beh laa no? |
 |
Ṣé ọmọ rẹ yà'gbẹ́ l'àná? |
 |
 |
Has your child had any diarrhea? |
 |
 |
sheh o mo reh ohn yaa Beh shee sho? |
 |
Ṣé ọmọ rẹ n yà'gbẹ̀ ṣíṣàn? |
 |
 |
Has your child been vomiting? |
 |
 |
sheh o mo reh ohn bee? |
 |
Ṣé ọmọ rẹ n bì? |
 |
 |
Your child looks healthy. |
 |
 |
o mo reh nee ee lay raa |
 |
Ọmọ rẹ ní ìlera |
 |
 |
Your child will be fine. |
 |
 |
o mo reh ma nee ee lay raa |
 |
Ọmọ rẹ ma ní ìlera |
 |
 |
Your child will be ill for a long time. |
 |
 |
aa raa o mo reh ko nee daa fU ee Ba Pee Peh |
 |
Ara ọmọ rẹ kò ní dá fún ìgbà pípẹ́ |
 |
 |
This illness will pass slowly, but your child's health will return completely. |
 |
 |
aa ee lay raa yee a maa lo dee eh dee eh, tee tee o mo reh ma fee nee ee lay raa Pa taa Paa taa |
 |
Àìlera yì í á má a lọ díẹ̀ díẹ̀, títí ọmọ rẹ ma fi ní ìlera pátápátá |
 |
 |
Feed the child small portions every few hours. |
 |
 |
fU o mo reh nee ohn jeh kay kay ray la aa rE waa kaa tee dee eh |
 |
Fún ọmọ rẹ ní oúnjẹ kékeré l'àárin wákàtí díẹ̀ |
 |
 |
Help your child drink this every few hours. |
 |
 |
raH o mo reh lo wo laa tee moo eh yee laa aa rE waa kaa tee dee eh |
 |
Ran ọmọ rẹ l'ọ́wọ́ láti mu èyí l'àárin wákàtí díẹ̀ |
 |
 |
Feed this medicine to your child every four hours. |
 |
 |
fU o mo reh nee eh Bo gee yee nee waa kaa tee may rE may rE |
 |
Fún ọmọ rẹ ní egbògi yì í ní wákàtí mẹ́rin mẹ́rin |
 |
 |
Allow your child to sleep. |
 |
 |
jeh kee o mo reh sU |
 |
Jẹ́kí ọmọ rẹ sùn |
 |
 |
You need to sleep as much as the child does. |
 |
 |
o nee laa tee sU bee o mo reh tee ohn sU |
 |
O ní láti sùn bí ọmọ rẹ ti n sùn |
 |
 |
Bring your child back here tomorrow. |
 |
 |
Beh o mo reh Pa daa waa lo laa |
 |
Gbé ọmọ rẹ padà wá l'ọ̀la |
 |