 |
Do you have any chest pain or tightness? |
 |
 |
sheh o nee ee ro raa aa ya taa bee in ko lee lay? |
 |
Ṣé o ní ìrora àyà tàbí nkan líle? |
 |
 |
Are you having trouble trying to breathe? |
 |
 |
sheh o nee ee daa moo laa tee mee? |
 |
Ṣé o ní ìdàmú láti mí? |
 |
 |
Do you have chest pain over your entire chest? |
 |
 |
sheh o nee ee roo raa nee BoBo aa yaa? |
 |
Ṣé o ní ìrora ní gbogbo àyà? |
 |
 |
Do you have pain from your chest into your arm? |
 |
 |
sheh o nee ee roo raa laa tee aa yaa tee tee deh a Paa? |
 |
Ṣé o ní ìrora láti àyà títí dé apá? |
 |
 |
Have you had this type of chest pain before? |
 |
 |
sheh o tee nee ee roo ee roo raa aa yaa baa yee ree? |
 |
Ṣé o ti ní irú ìrora àyà báàyí rí? |
 |
 |
Do you feel light-headed with the chest pain? |
 |
 |
sheh o jo wee Peh o ree reh foo ya Peh loo ee roo raa aa yaa no? |
 |
Ṣé ó jọ wípé orí rẹ fúyẹ́ pẹ̀lú ìrora àyà ná à? |
 |
 |
Do you sweat with the chest pain? |
 |
 |
sheh o maa ohn laa gU Peh loo ee roo raa aa yaa no? |
 |
Ṣé ó má a n là'gùn pẹ̀lú ìrora àyà ná à? |
 |
 |
This heart pill may give you a headache. |
 |
 |
eh Bo gee oo ko yee lay fa o ree fee fo fU eh |
 |
Egbògi ọkàn yì í lè fa orí fífọ́ fún ẹ |
 |
 |
This will go under your tongue. |
 |
 |
eh lay yee aa lo see a beh a hoH eh |
 |
Eléèyí á lọ sí abẹ ahọn ẹ |
 |
 |
Chew this and swallow it. |
 |
 |
jeh eh yee, kee o see Beh mee |
 |
Jẹ èyí, kí o sì gbemì |
 |