 |
Everything will be done to make you feel better again. |
 |
 |
BoBo ohn ko nee a ma sheh kee aa raa reh lay daa Pa daa |
 |
Gbogbo nkan ni a ma ṣe kí ara rẹ lè dá padà |
 |
 |
You are only slightly wounded. |
 |
 |
o sheh sheh dee eh |
 |
O ṣèṣe díè |
 |
 |
You will soon be up again. |
 |
 |
aa raa reh ma daa laa ee Peh |
 |
Ara rẹ ma dá láìpẹ́ |
 |
 |
Your condition is serious, but you will get better. |
 |
 |
ee po tee o wa yee lay gaH, sho BoH aa raa eh aa daa |
 |
Ipò tí o wà yì í le gan, sùgbọ́n ara ẹ á dá |
 |
 |
You will get better if you let us take care of you. |
 |
 |
aa raa eh aa daa tee o baa jeh kee a to jo eh |
 |
Ara ẹ á dá tí o bá jẹ́ kí a tọ́jú ẹ |
 |
 |
We will arrange for your transport back to your country. |
 |
 |
a ma sheh eh to bee o sheh ma Pa daa see o ree leh eh day reh |
 |
A ma ṣe ètò bí o ṣe ma padà sí orílẹ̀ èdè rẹ |
 |
 |
We will send you to another place. |
 |
 |
a ma Beh eh lo see ee bo meeraH |
 |
A ma gbé ẹ lọ sí ibòmíràn |
 |
 |
You need more care. |
 |
 |
aa raa reh feh ee to jo |
 |
Ara rẹ fẹ́ ìtọ́jú |
 |
 |
You will return to your Unit when you are better. |
 |
 |
waa Paa daa lo baa awoH eh Beh eh tee aa raa reh baa tee daa |
 |
Wà á padà lọ bá àwọn ẹgbẹ́ ẹ tí ara rẹ bá ti dá |
 |
 |
I will be back soon. |
 |
 |
mo ohn Pa daa bo laa ee Peh |
 |
Mò n padà bọ̀ láìpẹ́ |
 |
 |
I will check back later to see how you are doing. |
 |
 |
mo ma Pa daa laa tee wa wo aa laa fee ya eh |
 |
Mo ma padà láti wá wo àláfíà ẹ |
 |
 |
Return tomorrow so we can be sure you get better. |
 |
 |
Pa daa wa lo laa kee a lay mo Pay aa raa reh tee daa |
 |
Padà wá l'ọ́la kí a lè mọ̀ pé ara rẹ ti dá |
 |
 |
Return in one week so we can be sure you get better. |
 |
 |
Pa daa wa lo seh ko kee a lay mo Pay aa raa reh tee daa |
 |
Padà wá l'ọ́sẹ̀ kan kí a lè mọ̀ pé ara rẹ ti dá |
 |