 |
Do you have an identity card? |
 |
 |
sheh o nee kaa dee ee daa nee mo? |
 |
Ṣé o ní káàdì ìdánímọ̀? |
 |
 |
Show me your identification. |
 |
 |
fee kaa dee ee daa nee mo reh haH mee |
 |
Fi káàdì ìdánímọ̀ rẹ hàn mí |
 |
 |
Do you have any bad reactions to medications? |
 |
 |
sheh awoH eh Bo gee ko waa tee ko baa eh laa raa moo? |
 |
Ṣé àwọn egbògi kan wà tí kò bá ẹ l'ára mu? |
 |
 |
What is the name of the medication that causes bad reactions? |
 |
 |
kee nee oo roo ko eh Bo gee tee ko baa eh laa raa moo? |
 |
Kíni orúkọ egbògi tí kò bá ẹ l'ára mu? |
 |
 |
Do you have any allergies to medicines? |
 |
 |
sheh awoH eh Bo gee ko waa tee ko baa eh laa raa moo? |
 |
Ṣé àwọn egbògi kan wà tí kò bá ẹ l'ára mu? |
 |
 |
Do you have high blood pressure problems? |
 |
 |
sheh o nee ee daa moo eh jeh Boo Bo no? |
 |
Ṣé o ní ìdàmú ẹ̀jẹ̀ gbúgbóná? |
 |
 |
Do you have diabetes? |
 |
 |
sheh o nee daa yaa bee tee see? |
 |
Ṣé o ní dayabítìsì? |
 |
 |
Do you have blood sugar control problems? |
 |
 |
sheh o nee ee daa moo sho gaa Poo Po jo nee no eh jeh? |
 |
Ṣé o ní ìdàmú ṣúgà púpọ̀jù nínú ẹ̀jẹ̀? |
 |
 |
Do you drink alcohol? |
 |
 |
sheh o maa ohn moo o tee? |
 |
Ṣé ò má a n mu ọtí? |
 |
 |
How much do you weigh? |
 |
 |
baa wo nee o tee saH raa to? |
 |
Báwo ni o ti sanra tó? |
 |