|
If we do not operate, you may die. |
|
|
tee a ko baa sheh o Poo ray sho no, o lay ko |
|
Tí a kò bá ṣe opuréṣọ̀nù, o lè kú |
|
|
If we do not operate, you may lose this. |
|
|
tee a ko baa sheh o Poo ray sho no, woH maa geh eh yee nee |
|
Tí a kò bá ṣe opuréṣọ̀nù, nwọ́n ma gé èyí ni |
|
|
The operation is dangerous, but it is the only way to help you. |
|
|
o Poo ray sho noo yee lay woo, sho Bo ohn nee ko nee aa lay fee raH eh lo wo |
|
Opuréṣọ̀nù yì í l'éwu,ṣùgbọ́n òhun nìkan ni a lè fi ràn ẹ́ lọ́wọ́ |
|
|
Do you understand that you need this surgery? |
|
|
sheh o yee eh Pay ohn lo see a beh a beh? |
|
Ṣé o yé ẹ pé ò n lọ sí abẹ́ abẹ? |
|
|
We will operate very carefully. |
|
|
aa maa fee so roo sheh o Poo ray sho no fU eh |
|
A ma fi sùúrù ṣe opuréṣọ̀nù fún ẹ |
|
|
We want your permission before we operate on you. |
|
|
fU wa nee a yee laa tee sheh o Poo ray sho no fU eh |
|
Fún wa ní àyè láti ṣe opuréṣọ̀nù fún ẹ |
|
|
May we operate on you? |
|
|
sheh a lay sheh o Poo ray sho no fU eh? |
|
Ṣé a lè ṣe opuréṣọ̀nù fún ẹ? |
|
|
We will begin the operation as soon as we can. |
|
|
a maa bay reh o Poo ray sho no laa ee Peh |
|
A ma bẹ̀rẹ̀ opuréṣọ̀nù láìpẹ́ |
|
|
This medicine will make you sleep. |
|
|
eh Bo gee yee aa jeh ko so |
|
Egbògi yì í á jẹ́ ko sún |
|
|
Have you had any surgeries? |
|
|
sheh woH tee sheh ee sheh a beh fU eh ree? |
|
Ṣé nwọ́n ti ṣe iṣé abẹ fún ẹ rí? |
|