 |
You have been hurt. |
 |
 |
o tee sheh sheh |
 |
O ti ṣèṣe |
 |
 |
We are all working to help you. |
 |
 |
BoBo wa ohn shee sheh laa tee raH eh lo wo |
 |
Gbogbo wa n ṣiṣẹ́ láti ràn ẹ́ lọ́wọ́ |
 |
 |
Help us take care of you. |
 |
 |
raH waa lo wo laa tee to jo eh |
 |
Ràn wá lọ́wọ́ láti tọ́jú ẹ |
 |
 |
We have to remove your clothes. |
 |
 |
a nee laa tee bo a sho eh |
 |
A ní láti bọ́ aṣọ ẹ |
 |
 |
Do you have any bad reactions to any medicine? |
 |
 |
sheh awoH eh Bo gee ko waa tee ko baa eh laa raa moo? |
 |
Ṣé àwọn egbògi kan wà tí kò bá ẹ l'ára mu? |
 |
 |
Have you eaten food in the past six hours? |
 |
 |
sheh o tee jeh ohn laa rE waa kaa tee mee faa tee oo ko jaa? |
 |
Ṣé o ti jẹun láàrin wákàtí mẹ́fà tí ó kọjá? |
 |
 |
Is this injury from a landmine? |
 |
 |
sheh o ree PaPa tee o lay woo nee o tee sheh sheh? |
 |
Ṣé orí pápá tí ó l'éwu ni o ti ṣèṣe? |
 |
 |
Were you shot? |
 |
 |
sheh woH yE boH fU eh nee? |
 |
Ṣé nwọ́n yìnbọn fún ẹ ni? |
 |
 |
Is this from a knife? |
 |
 |
sheh a Paa o beh nee eh yee? |
 |
Ṣé àpá ọ̀bẹ ni éyí? |
 |
 |
Is this from a rock? |
 |
 |
sheh a Paa oo koo ta nee eh yee? |
 |
Ṣé àpá òkúta ni éyí? |
 |
 |
Is this from a vehicle crash? |
 |
 |
sheh a Paa laa tee eh woo oo ko nee eh yee? |
 |
Ṣé àpá láti éwu ọkọ̀ ni éyí? |
 |
 |
Did a person do this to you? |
 |
 |
sheh eh nee yaH ko lo sheh eh lay yee? |
 |
Ṣé ènìyàn kan ló ṣe eléèyí? |
 |
 |
Did you lose consciousness after this happened? |
 |
 |
sheh o daa koo leh yE ee Baa tee eh lay yee sheh leh? |
 |
Ṣé o d'ákú lẹ́hìn ìgbà tí eléèyí ṣẹlẹ̀? |
 |
 |
Did you lose more than this much blood? |
 |
 |
sheh eh jeh yo jo eh lay yee lo? |
 |
Ṣé ẹ̀jẹ̀ yọ ju eléèyí lọ? |
 |
 |
Point to all the parts of your body that hurt. |
 |
 |
no wo see BoBo ee bee tee o on dU eh |
 |
N'ọwọ́ sí gbogbo ibi tí ó n dùn ẹ́ |
 |