 |
This will help you. |
 |
 |
eh lay yee aa raH eh lo wo |
 |
Eléèyí á ràn ẹ́ lọ́wọ́ |
 |
 |
I have to put a small needle in you here. |
 |
 |
mo maa gU eh laa beh reh nee bee |
 |
Mo ma gún ẹ l'abẹ́rẹ́ níbí |
 |
 |
We need to give you fluid. |
 |
 |
a nee laa tee fU eh nee o mee aa raa |
 |
A ní láti fún ẹ ní omi ara |
 |
 |
We need to give you blood. |
 |
 |
a nee laa tee fU eh nee eh jeh |
 |
A ní láti fún ẹ ní ẹ̀jẹ̀ |
 |
 |
I need to put a tube into your throat. |
 |
 |
mo nee laa tee fee pa ee poo yee see o fU eh |
 |
Mo ní láti fi páìpù yì í sí ọ̀fun ẹ |
 |
 |
This tube will help you breathe better. |
 |
 |
paa ee poo yee aa raH eh lo wo laa tee mee daa daa |
 |
Páìpù yì í á ràn ẹ́ lọ́wọ́ láti mí daada |
 |
 |
This tube may feel uncomfortable. |
 |
 |
paa ee poo yee lay maa deh roo |
 |
Páìpù yì í lè má dẹrùn |
 |
 |
I need to put a tube through your nose to your stomach. |
 |
 |
mo nee laa tee moo paa ee poo yee Ba ee moo eh lo see ee kU |
 |
Mo ní láti mú páìpù yì í gba imú ẹ lọ sí ikùn |
 |
 |
You need to swallow while I put this tube in your nose. |
 |
 |
o nee laa tee Beh mee tee ohn baa tee ohn moo paa ee poo yee see ee moo eh |
 |
O ní láti gbémì tí n bá ti n mú páìpù yì í sí imú ẹ |
 |
 |
Drink this while I gently place the tube into your nose. |
 |
 |
moo eh yee kee ohn fee so roo moo paa ee poo yee see ee moo eh |
 |
Mu èyí ki n fi sùúrù mú páìpù yì í sí imú ẹ |
 |
 |
This tube will drain your stomach. |
 |
 |
paa ee poo yee a Bo o mee koo roo nee kU eh |
 |
Páìpù yì í á gbọ́n omi kúrò ní'kùn ẹ |
 |
 |
I have to put a small tube into your neck to give you fluid. |
 |
 |
mo tee fee paa ee poo kay kay ray see o roo eh laa tee fU eh nee o mee |
 |
Mo ti fi páìpù kékeré sí ọrùn ẹ láti fún ẹ ní omi |
 |
 |
I need to put a tube in your chest. |
 |
 |
mo nee laa tee fee paa ee poo see aa yaa eh |
 |
Mo ní láti fi páìpù sí àyà ẹ |
 |
 |
This needle will release the air from your chest. |
 |
 |
a baa reh yee maa jeh kee a feh feh raa yee Ba jaa day |
 |
Abẹ́rẹ́ yì í ma jẹ́ kí afẹ́fẹ́ r'áyè gbà jáde |
 |
 |
This will help your burns. |
 |
 |
eh lay yee aa raH eh lo wo fU aa raa reh tee o jo |
 |
Eléèyí á ràn ẹ́ lọ́wọ́ fún ara rẹ tí ó jó |
 |
 |
I need to cut your skin. |
 |
 |
mo nee laa tee laa aa raa eh |
 |
Mo ní láti la ara ẹ |
 |
 |
We have to restrain you for your safety. |
 |
 |
a nee laa tee dee eh moo fU ee daa bo bo |
 |
A ní láti dì ẹ́ mú fún ìdábòbò |
 |
 |
You have been burned by a chemical. |
 |
 |
ka mee kaa lee tee jo eh |
 |
Kẹ́míkàlì ti jó ẹ |
 |
 |
We need to wash the chemicals from your skin. |
 |
 |
a nee laa tee fo awoH ka mee kaa lee koo roo laa raa eh |
 |
A ní láti fọ àwọn kẹ́míkàlì kúrò l'ára ẹ |
 |
 |
You will need to be completely washed. |
 |
 |
a nee laa tee weh eh mo daa daa |
 |
A ní láti wẹ̀ ẹ́ mọ́ dáada |
 |
 |
Hold this dressing and apply pressure. |
 |
 |
dee baan day jee yee moo kee o see fee a Baa raa teh mo leh |
 |
Di bándèjì yì í mú, kí o sì fi agbára tẹ̀ ẹ́ mọ́'lẹ̀ |
 |
 |
I need to splint your arm. |
 |
 |
mo nee laa tee fee ohn ko Beh o wo eh do roo |
 |
Mo ní láti fi nkan gbé ọwọ́ ẹ dúró |
 |
 |
I need to splint your leg. |
 |
 |
mo nee laa tee fee ohn ko Beh eh seh eh do roo |
 |
Mo ní láti fi nkan gbé ẹsẹ̀ ẹ dúró |
 |
 |
I am applying a tourniquet to stop the bleeding. |
 |
 |
mo nee laa tee fee ee gee haa kee eh jeh lay daa |
 |
Mo ní láti fi igi há a kí ẹ̀jẹ̀ lè dá |
 |