 |
You must stay in this room. |
 |
 |
o nee laa tee do roo see yaa raa yee |
 |
O ní láti dúró sí yàrá yì í |
 |
 |
You must not smoke. |
 |
 |
maa sheh moo see gaa |
 |
Má ṣe mu sìgá |
 |
 |
We have to cut your hair off here. |
 |
 |
a nee laa tee geh ee rU eh koo roo nee bee |
 |
A ní láti gé irun ẹ kúrò níbí |
 |
 |
You may get up to go to the toilet. |
 |
 |
o lay dee day lo see ee lay ee Beh |
 |
O lè dìde lọ sí ilé ìgbẹ́ |
 |
 |
We cannot give you anything to eat or drink. |
 |
 |
a ko lay fU eh nee ohn ko jee jeh taa bee mee moo |
 |
A kò lè fún ẹ ní nkan jíjẹ tàbí mímu |
 |